Gbajúgbajà elétíofe tí gbogbo ayé mò sí Linda Ikeji tí ó sèsè bí omo okúnrin rè ní ojó ketàdínlógún osú kesàn-án odún tí a wà yí, pín àwòrán sí orí èro insítágírámù pèlú omo rè, Jayce. Ó ko síbè wípé… ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
Awoyemi Bamimore Comments Off on Linda Ikeji àti omo rè, tí orúko omo náà n jé Jayce Jeremi nínú àwòrán tuntun.
Gbajúgbajà elétíofe tí gbogbo ayé mò sí Linda Ikeji tí ó sèsè bí omo okúnrin rè ní ojó ketàdínlógún osú kesàn-án odún tí a wà yí, pín àwòrán sí orí èro insítágírámù pèlú omo rè, Jayce. Ó ko síbè wípé… ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ibon !
Awoyemi Bamimore Comments Off on Ògúndá Ọ̀wọ́nrín (Ògúndẹ̀rín)
Àtẹ́lẹwọ́ mi ọ̀tún ni mo fi kọ́’fá ń dídá Mo mọ Ifá ń dídá A dífá fún Akítán tíí ṣe ọmọ’yè Oníkàá Àtẹ́lẹwọ́ mi òsì ni mo fi kọ́bò ní gbígbà Mo mọ ìbò ni gbígbà Dífá fá fún Aṣọ̀gbà ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ejìnrìn Wọ̀jọ ̀wọ̀jọ̀
Ejìnrìn wọ̀jọ ̀wọ̀jọ̀ Awo Ọlọ́wọ̀ ló ṣefá fún Ọlọ́wọ̀ Eléyìí tí yóò roko roko tí yóò gbé kílìṣí tíí ṣe yèyé ajé wálé Ìji lẹ́lẹ́ – Awo Ìji lẹ́lẹ́ Ìji lẹ̀lẹ̀ – Awo Ìji lẹ̀lẹ̀ Ẹ̀fúùfù lẹ̀lẹ̀ ní jági lọ́run ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Stephanie Hornecker wo aso tí oyàn rè n hàn feere níbè, tí ó sì dàbí egbin nínú è
Stephanie Hornecker wo aso tí oyàn rè n hàn feere níbè, tí ó sì dàbí egbin nínú è. Arewà télè tí ó tún jé òsèré orí ìtàgé sùgbón tí ó ti di Olùwòsàn báyìí, Regina Askia pín àwòrán tí ó ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ànto Lecky wo Ejò rògbòdò yíká orún rè
Ará ilé Bbnaija télè tí a mò so Anto ti gbé àrà òtun yo fún àwon olólùfé rè, nígbà tí ó lo sí àgbàlà ejò rògbòdò ní orílè èdè Republic of Benin. Ó ko síbè wípé: ” Ní àgbàlá ejò ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Yorùbá dún
Hà à à!! Elédùmàrè ìgbà wo l’ènìyàn yόò to bo nínú hílàhílo òde ayé yìí nà? Ki baálé ilé jáde láti òwúrò kùtùkùtù àná kό sí ma b’ojú wéhìn wo, Ǹjé irú ìwà béè daa?? Àmò sà à!! Èyí tà ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on È má jé kì olá èro ayélujára tàn yín je- báyìí ni Joke Silva wí.
Nínú ìfòròwánilénuwò nínú ìwé ìròyìn ti Genevieve Nnaji tí won se fún ognóntàrigì òsèré orí ìtàgé tí a mò sí Joke Silva, ni ó ti gba àwon èèyàn ní ìmòràn kí won má se jé kí ohun tí àwon elégbé ...
Read More »Òkè olúmo jé òkè kan gbòógì tí a kò le fi owó ró séyìn nínú àwon òkè tí n be ní orílè èdè Nìjíríà, kìí wá se orílè èdè yí nìkan ni a kò tile fi owó ro séyìn bí ...
Read More »Àwon àjo tí ó n mójú tó ètò ìdìbó tí a mò sí INEC ti kéde Gboyega Oyetola gégé bí eni tí ó gbégbà orókè níbi ìdìbò tí won tún dì ní àná. Omo egbé oní ìgbálè tí won fà ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more