Oun tí ó ba ni nínújé gbáà ni ìsìnkú okùnrin kan pèlú ìyàwó rè àti omokùnrin won tí ó kú ní ojó kan náà. A gbó wípé ojó kan náà ni won ma sin wón ní ìpínlè Imo. Èyí ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
Awoyemi Bamimore Comments Off on Òbísúárì okùnrin kan, ìyàwó rè pèlú omokùnrin won tí a gbó wípé won sin won ní ojó kan náà .
Oun tí ó ba ni nínújé gbáà ni ìsìnkú okùnrin kan pèlú ìyàwó rè àti omokùnrin won tí ó kú ní ojó kan náà. A gbó wípé ojó kan náà ni won ma sin wón ní ìpínlè Imo. Èyí ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ère Nana Akufo- Addo ni Rochas Okorocha fé sín ní Imo.
Gómìnà ìpínlè Imo, Rochas Okorocha ti se tán láti sín ère ààre Nana Addo ti Ghana ní Owerri nígbà tí ó ti sí ère ti ààre Ellen Sirleaf ti Laberia àti Zuma ti South Africa . Ère náà ti ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Destiny Etiko wo sòkòtò bénbé pèlú aso yí ó ba mu.
Òsèré Nàíjíríà tí a mò sí Etiko Destiny ti jáde láì wo Kómú. Òsèré yí wá gbe lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán tí kò wo Kómú yí.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Gómìnà Obaseki se ayeye odún kan tí ó ti dé ipò, Akeredolu àti Amaechi náà sì ba yò.
Gómìnà ìpínlè Ondo, Akeredolu lo bá Gómìnà ìpínlè Edo se àjoyò odún kan tí ó dé ipò ní pápá Samuel Ogbemedia, Benin city.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.
Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Regina Daniel rewà ó sì dàbí àgbàlagbà níbi àwòrán tuntun tí ó sèsè yà.
Òdóbìnrin òsèré yí, Regina Daniel ti gbe lo sí orí ìtàn èro ayélujára (insta-stories) láti pín àwòrán tí ó ti yàtò yí.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Sandra Okagbue ya orúko flavour “Chinedu” sí owó rè .
Ìyá omo olórin flavour, Sandra tàtúù orúko rè “Chinedu” sí apá .
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ajá mi , pitbull pa Àntà tí ó n sólé ,obè ti délè oo.
Èrín pa mí, ajá mi, pitbull pa á lónìí , ta ló fé?
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí won yà nínú omi adágún.
Odára àbí kò dára?
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìjàmbá okò tírélà tí ó selè tí ó sì se òpò èèyàn lese ní Gombe.
Èyí ni ìsèlè tí ó selè láìpé ní ojó kejìlá osù kokànlá odún yí ní Gombe ní ìpínlè Gombe tí tírélà fà . lóòtó kò sí eni tí ó kú, sùgbón òpò ni ó se Lése gan. A ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more