Ni igbà àtijọ́, ẹranko ti wọn pè ni Ẹkùn jẹ alágbára ẹranko, bẹni Kìnìún si jẹ́ alágbára ẹranko. Bi Kìnìún ti lágbára tó ninú igbó, bi ó bá bú ramúramù, ohun gbogbo ninú igbó á pa kẹ́kẹ́ titi dé ori ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Ẹ̀rù ló sọ ọmọ Ẹkùn di Ológbò/Ológìní tó fi di ” Ẹran-àmúsìn – Ọdẹ peku-peku” –
Ni igbà àtijọ́, ẹranko ti wọn pè ni Ẹkùn jẹ alágbára ẹranko, bẹni Kìnìún si jẹ́ alágbára ẹranko. Bi Kìnìún ti lágbára tó ninú igbó, bi ó bá bú ramúramù, ohun gbogbo ninú igbó á pa kẹ́kẹ́ titi dé ori ...
Read More »ayangalu Comments Off on “Àṣejù Baba Àṣetẹ́” – Ìtàn bi Ojúkòkòrò àti Ìgbéraga ti jẹ́ Àṣejù
Ni ìgbà àtijọ́, ọkùnrin kan wa ti orúkọ rẹ njẹ́ Ìgbéraga. Wọ́n bi Ìgbéraga si ilé olórogún, àwọn ìyàwó bàbá́ rẹ yoku ni ó tọ nitori ìyá rẹ kú nigbati ó wà ni kékeré. Lẹhin ti o tiraka lati pari ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iwure Fun Wa Latari Bi A Se Mo Ise Aburu Ti Awon Elenini Nse Lati Ma Fe Jeki Eniyan Se Rere Ati Saseyori Nile Aye,
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun ku imura toni, mo gbaladura laaro yi wipe gbogbo awon ota ti won ba sope ako ni se rere yio di gige kuro lori ile alaaye loni ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ifa naa ki bayi wipe
Aku ise ana o a si tun ku amojuba osu tuntun o, eledumare yio jeki osu yi tuwa lara o, ako ni bawon paruwo kosi kosi lase eledumare. Laaro yi mo maa fi odu mimo ejioore se iwure fun yin ...
Read More »ayangalu Comments Off on Irete Iwori ati Iwori Obara !
Irete Iwori Isu ire lo se e je epo Epo ire lo se e je isu obinrin du-un ba sun ju bi o ba ba okunrin sun bii koko bii eewo bii IKU bii agbaarin bi o ba ba obinrin ...
Read More »ayangalu Comments Off on Oro Nipa Ose Olubadan: Idi Ti Egúngún Kankan Ko Se Nde Oja Oba Ibadan Di Oni Oloni Mo
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi opin ose oni, adura wa yio je itewogba lodo eledumare o Ase. Laaro yi mofe se idanileko nipa idi to fi je wipe egungun kankan ko se nde oja oba ibadan mo ...
Read More »ayangalu Comments Off on Obi ni nii Ofo !!
Obi ni bii Iku Obi ni bii Arun Obi ni nii Ofo Kolanut avert death Kolanut avert illness/disease Kolanut avert loss Obi(Kolanut) is sacred. He who bring Kolanut brings joy. Ase Ire O!!!
Read More »ayangalu Comments Off on Iwure: Odu Okanransode
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Abu ise ana o a si tun ki orire iwonu ose tuntun, ose yi yio san wa si ire gbogbo ako ni to ona iparun lose yi o ase. Laaro yi mo maa fi ...
Read More »ayangalu Comments Off on Igunuko !
ayangalu Comments Off on Orunmila soro nipa ikin ifa !
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o a sin ku isimi opin ose, bi a se nwonu aye loni ako ni pare maye lara o ase. Laaro yi mo fe fi akoko yi fesi si ibeere awon ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more