ri ………Ohun gbogbo lowo ori eni. Ori mi ma pada leyin mi. Ojumo Ire o!
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Isebo ni isegun baa ti waye pa a ri, la a
ri ………Ohun gbogbo lowo ori eni. Ori mi ma pada leyin mi. Ojumo Ire o!
Read More »ayangalu Comments Off on Ose tu’a
ko-mi-koro awo Ewi l’Addo Orun koko-ko awo Ijesa m’Okun Alakan nigbo ‘do t’eye ifá kerekere-kere adi’a fun Igba Irunmole ajikotun obu okan fun Igba Imole ajikosi alukin fun Orunmila nijo ti won ti Isalu orun bo wa Isalu aiye Eledumare ...
Read More »ayangalu Comments Off on APINTANBI
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun Ku isimi opin ose eledumare koni jeki a fi eleyi se asemo o ase. Laaro yi mo fe so die nipa oro APINTANBI ti awon opuro ati ...
Read More »ayangalu Comments Off on Isu Oro bale ro pee…
A da fun eji, ti o ma bowo fun iko Odidere, won ni ko kara nile, Ebo ni ko mu se. Ojo o ni ro ko pa ina iko Odidere, Iko Odidere d’Orisa. Ni Agbara Olodumare ati oruko Orunmila, Gbogbo ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ibi ti ilę ti fę !
Oju Opon Ifa.
Read More »ayangalu Comments Off on Otura Oriko, wa lo ree silekun ire temi fun mi! Aase!
Hoje também é dia de propiciarmos Olokun. Que a força e o Ase de Olokun abra as portas do progresso e da prosperidade a nossa família criando condições para que todos os obstáculos sejam retirados de nosso caminho. Ikan lowo ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ewe Yi Je Òkan Lara Awon Ewe Ifa To Dara Pupo
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin ku isimi opin ose, emin wa yio se pupo re laye ase. Laaro yi mofe ki a mo iwulo ewe to wa ninu aworan yi lati inu odu ...
Read More »ayangalu Comments Off on Atitare/Itare: Pataki ewe towa ninu aworan yi ninu odu ifa OTURA ORILANA
Aku ise ana o oni a sanwa o, aanu olorun Olodumare koni fiwa sile loni o ase. Laaro yi mofe ki e mo Pataki ewe towa ninu aworan yi ninu odu ifa OTURA ORILANA, ati iwulo e ti o se ...
Read More »Ejo kini oruko ewe yi
Read More »ayangalu Comments Off on Oriki Ori…
Ori Onise Apere Atete gbeni ju Orisa Ori atete niran Ori lokun Ori nide Ko si Orisa ti dani gbe leyin Ori eni Ori ni seni ta a fi dade owo Ori ni seni ta a fi tepa ileke woja ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more