Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Eku ojo meta o, Ogun lakaye yio bawa segun awon ota wa yio si lana ire gbogbo funwa loni ase. Odu ifa iwure toni ki bayi wipe: Irete Osa kubu irete Osa kebe, irete ...
Read More »Ayeye Ojoibi Toni: Babami Oloye Olatbosun Oladapo
Ododun larorogbo Ododun lari awusa Ododun lati mo obi lori ate Ododun ni sapo nruwe Ododun ni peregun yio Ododun leo ma bee ninu ola ati Alaafia Alekun ogbon Alekun Oye Alekun IMO Alekun emi gigun Alekun Alaafia Oju asa ...
Read More »Ori mi segbe leyin mi ooo..
Ori eni lawure eni ni, Ori mi segbe leyin mi ooo. Ori a gbe wa o.Ase oo
Read More »Odu Ifa Iwure Ti Aaro Yi Ki Bayi Wipe
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tu ku imura toni eledumare koni jeki won gberu ibanuje wa kawa mole loni o ase. Odu ifa iwure ti aaro yi ki bayi wipe: Oseka ori odi ...
Read More »Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose ...
Read More »Ipade! Ipade! Ipade!
“Mo se ileri fun orisun mi Ti I se ile yoruba, Lati je omo yoruba atata nileloko, Ati lati je omo oko, Ti ki I f’owo osi Juwe ile baba re, Lati gbe ise, asa Ati ede yoruba laruge, Nibi ...
Read More »Pari owe yii..
Bi ọdẹ ba ro iṣẹ, ro iya, boba pẹran ………..
Read More »Ogulutu Oro Toni – 11.09.2016
Hummmmmm ile eni lati nje ekute oni dodo, Morojo oko re feni kankan mo Tori Kosi bi tise o si oni kaluku naa nfaso bo tie ni wara o si loni, wara nbo lola Woo Orewa Kosokunrin tope nile aiye ...
Read More »Odu Ifa Iwure Toni Ki Bayi Wipe…
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, oni a sanwa sire gbogbo o ase. Odu ifa iwure toni ki bayi wipe: Òkan fìkìkìkì babalawo oladeji difa fun oladeji eyiti won nfojojumo njuwe re fun iku, won ni ...
Read More »