Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Alagba Oluwakayode Olamilekan Adekoya Ijeni ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba. Okan pataki ni won je lara awon majekobaje ilu yi, oloye nla niwon laafin Olumoye. ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Olojo Ibi Toni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Alagba Oluwakayode Olamilekan Adekoya Ijeni ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba. Okan pataki ni won je lara awon majekobaje ilu yi, oloye nla niwon laafin Olumoye. ...
Read More »Ojuwo lefi wo asa ila kiko laiye #IJOHUN ati #AIYE_ISIN …..nje odara kamo ko omo wa nila bi???
Read More »ayangalu Comments Off on Sacrifice (Ebọ; Etutu)
Sacrifice (Ebọ; Etutu) Medium: Chinese Bamboo on bond paper Atelewọ ni o hu’run hèùhèù Dia fun Mofẹ́ẹ́ní Tín bẹ láàrín Òsììrí Tín bẹ láàrín ìpọ́njú To wá nlọ rèé k’owó lọ’dọ̀o Kìífẹání Ẹbọ ni wọ́n ní kó ṣe O gbẹ́bọ, ...
Read More »ayangalu Comments Off on Yoruba Du ‘n ka
Yoruba dun-un ka yoruba e komo yin o, ko tun le ko ko tun le so ede abinibi. A~ AJA, B~ BATA, D~ DOJE, E~ EJO, E~EYE, F~ FILA, G~ GELE………. A B D E E F G GB H ...
Read More »ayangalu Comments Off on Odu merindilogun re o
ayangalu Comments Off on Foto: Ara Kenge !
E bami kira fun Ife….gbosa, gbosa, gbosa
Read More »ayangalu Comments Off on Orin, Owe ati Ewi !
ORIN : ” Ododo-Eye mi, ko ma re danu .. Ko maa re danu, Loju aye mi.. Ile nimo ko o, Oko nimo ra.. Omo,Omo l’adele o… …… OWE : * Agba waa bura bewe o ba se-o ri. * ...
Read More »ayangalu Comments Off on Lakurubututu ! “Omo ya jo, omo le yeni”
Omolade,Omolowo,Omolola,Omo ni ola,Omoni’yi Omo’leye, Omolabake, Omolabage, Omopariola Omojowolo, Omosunbo, Omofowokade, Omofowokola Omotoriola, Omorinsola, Omorinsoye, Omobobola, Omoyosola Omoboboye, Omoyosade,Omoyosoye, Omodapomola, Omodapomoye Omoboriola, Omoboriola,Omotanshe,Omotanoshi, omo ju oun gbogbo lo, Aakun dabo ore wa toju omo re nitori awon ni Ojo ola re, ...
Read More »ayangalu Comments Off on Idile Alayo: E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ounje UNJE Eme Fun T’ooro Yii – 26.05.2016
HUN ! B’o ti wu ki a pe laye to … A pee lorun ju bee lo… :::: WOO ORE WA ! #Igba o lo bi #Orere.. Bee, #Laye taa wa yii ko lo bi #Opa_ibon ::::::: DAKUN ORE WA ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more