Oba Babatunde Enitan Adeyeye Ogunwusi Ojaja II
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
admin Comments Off on Awon foto lati ibi iwuye Oba Adeyeye Enitan, Ooni ti Ile-Ife (Apa-Keji)
Oba Babatunde Enitan Adeyeye Ogunwusi Ojaja II
Read More »admin Comments Off on Ile ejo to gaju lo ni yoo pari idaju iku Reverend King
Ile ejo to gaju nile yii ti kede ojo kerindinlogbon osu keji odun ti n bo (26/02/15) gege bi ojo ti igbejo adari ijo Christian Praying Assembly, Reverend Chukwuemeka Ezeugo, ti gbogbo eniyan mo si Reverend King yoo ma waye. ...
Read More »admin Comments Off on E kaabo si aafin Ooni Adeyeye Enitan Ogunwusi
E kaabo si aafin Ooni Adeyeye Enitan Ogunwus
Read More »admin Comments Off on Gobe sele lagbo Davido
Orisiirisii ara ni awon omo olorin igbalode maa n da lagbo ere orin. Iru ara bee ni bi ki won bo aso lorun ki won si ju si aarin ero onworan. Awon mii a maa bo alakorun danu soju agbo ...
Read More »admin Comments Off on “Oruko awon to ja Naijiria lole ko ni pe jade” – Buhari
Aare Buhari ti fi da awon omo Naijiria loju wi pe, laipe, awon oruko awon ojelu ti won ko owo Naijiria je ko ni pe di tite jade fun gbogbo aye. Gege bi oro re, eleyii to se nibi ipade ...
Read More »admin Comments Off on Oselu ipinle Oyo: Alao Akala ti wa ogbon mii da
Christopher Alao Akala ti wa ogbon mii da Nibayii ti Christopher Alao-Akala, eni odun marunlelogota (65) ti pinnu lati darapo mo egbe APC lati inu egbe Labour Party ni awon awuyewuye kan ti bere si ni jeyo jade. Lara awon ...
Read More »admin Comments Off on Iriri awon omuti: Ore meji ku, iketa fara pa
Gege bi oro awon Yooba,”eni Sango ba toju re wole, eni naa ko ni ba won bu oba Koso laelae.” Okunrin kan to pe ara re ni Cde Zenzele Nkosi lori FACEBOOK lo salaye ijamba moto to sele si i ...
Read More »admin Comments Off on Igba otun ti de: Raji Fasola ti bo soju ise
Minisita fun ina Monamona, Ise Ode, ati Ilegbee, Babatunde Raji Fasola ti kede eto ati awon igbese re akoko eleyii ti o fi ma side ise ilu ti won gbe le e lowo gege bi minisita. Gege bi gomina eleeketala ...
Read More »admin Comments Off on #EsuIsNotSatan: I’m ESu Ola Ilu (Must Read)
I am one among the delegated Irunmoles of Olodumare Therefore, I am a messenger of Olodumare I stand as intermediary between Ajoguns to the Orisa and Omo Eniyan I stand as prosecutor to defaulters of the Instructions of Olodumare You ...
Read More »admin Comments Off on What is Ifá’s position on GAY marriage?
My RESPONSE to the very much insistently asked questions from friends and associates, within and mostly outside Indigenous Faith of Africans believers ( IFA ), on Ifá’s position about the global ranting GAY marriage that has arouse much confrontations between ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more