Eniyan le fi ebi kose owo, sugbon ko rorun lati febi kawe. Wahala igo ni o pa alasuota. Ise akanse, ka ji kawe loru, lo soke lo sode, ka sare wo kilaasi losan pon ganrin-ganrin ni o je komo ile ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
admin Comments Off on Won we ose awure fomo Poli Ibadan
Eniyan le fi ebi kose owo, sugbon ko rorun lati febi kawe. Wahala igo ni o pa alasuota. Ise akanse, ka ji kawe loru, lo soke lo sode, ka sare wo kilaasi losan pon ganrin-ganrin ni o je komo ile ...
Read More »admin Comments Off on #OGULUTU: Olaju ti so ogbon aye atijo di omugo patapata
E ku asiko yii eyin eniyan mi, ko to di wi pe n maa se alaye ara mi tabi abala Ogulutu to je tuntun to gori Iwe Iroyin Owuro. E je n sare bi yin nipa oun ti won pe ...
Read More »admin Comments Off on Kayeefi niluu Eko: omokunrin ti o lese n wa danfo
Kayeefi niluu Eko: omokunrin ti o lese n wa danfo. E le ka ero awon eniyan nipa okunrin yii nibi:
Read More »admin Comments Off on Ere Opolo: Matimatiisi to gbona felifeli
Ile itaja kan n ta masiini okada ati keke maruwa. Apapo gbogbo oja ti won ni je. meje (apapo okada ati keke maruwa), gbogbo oja won lapapo si ni taya mokandinlogun. Nje o le so iye okada ati keke maruwa ...
Read More »admin Comments Off on Ti o ba je wi pe emi ni Oliseh, ohun ti maa se ni wi pe…”- Adegboye Onigbinde
Vincent Enyeama ti n mu goli fun egbe agbaboolu Super Eagles ti dagbere fun egbe agbaboolu naa wi pe o digba kan na leyin odun metala to ti n sise sin ilu baba re. Igbese ikede ifeyinti pajawiri Enyeama ko ...
Read More »admin Comments Off on Diepreye Alamieyeseigha, gomina ipinle Bayelsa nigba kan ri, jade laye leni odun mejilelogota (62)
Diepreye Alamieyeseigha, to je gomina ipinle Bayelsa nigba kan ri, ti jade laye leni odun mejilelogota (62) lana Satide. Iroyin to te Olayemi Oniroyin lowo fi ye wa wi pe aisan ejeruru lo pa gomina naa.
Read More »admin Comments Off on Kayeefi: Adigunjale jabo lati oke aja banki sileele niluu Ilorin
Orisun Okunrin afura si gege bi olosa kan lo jabo lati inu aja ile ifowopamo Guaranty Trust to wa niluu Ilorin lojo Eti to koja (09/10/15). Kayeefi nla lo jo loju gbogbo awon eniyan to wa ninu banki ni akoko ...
Read More »admin Comments Off on Owo Ba awon igara olosa ti won fi okada sise ole L”Abuja
Owo te awon igara olosa meji kan ti won fi okada jawo gba loju opopona IBB to wa ni agbegbe Maitama niluu Abuja lojo Tuside to koja yii. Ile ifowopamo kan to wa ni opopona IBB ni enikan to je ...
Read More »admin Comments Off on Ebola seruba awon eniyan niluu Calabar
O kere tan, awon eniyan bi mewaa ni won ti se ayewo fun bayii niluu Calabar latari wi pe won ni ibapade pelu okunrin kan ti won fura si wi pe oseese ko ni arun Ebola. Okunrun ti won fura ...
Read More »admin Comments Off on Rose Odika setan lati se igbeyawo leyin iya-n-dagbe odun mewaa: Bobo kan lo jamo lowo niluu Eko
Leyin bi odun mewaa ti Rose Odika ti wa gege bi iya-n-dagbe, oserebirin omo Ipinle Delta naa ti setan lati ni oko tuntun. Bi o tile je wi pe bonkele ni won fi oro naa se, ti won si n ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more