Home / Art (page 100)

Art

Genevieve Nnaji

Genevieve Nnaji ya àwòrán pèlú àwon agbófinró obìnrin méjì .

Genevieve Nnaji ya àwòrán pèlú àwon agbófinró obìnrin méjì . Gbajúgbajà òsèré, Genevieve Nnaji tí ó dàbí egbin nígbà tí ó ya àwòrán pèlú àwon agbófinró obìnrin méjì yí . Òsèré yí ni ó pín àwòrán yí sí orí èro ...

Read More »
Oba Edu Isese Agbaye

Congrats!!! Meet the new Oba Edu Isese Agbaye, Faniyi David Osagbamii​

All the administrators and members of the Ooduarere.com and University of Ifa are proud of Baba Awo Faniyi David Osagbamii​, recently installed the Oba Edu Isese Agbaye. We congratulate you from the bottom of our hearts.  

Read More »

Àwòrán èyìn Chidinma Ekile tí ó rewà .

  Òrò tí ó gbòde kan ni wípé Chidinma Ekile ti darapò mó egbé burúkú àti wípé ó ti n kégbékégbé látàrí wípé ó ya tàtúù dí èyìn rè . Chidinma Ekile níbi ayeye kan tí ó wo aso tí ...

Read More »

Arewà tí ó se ìgbéyàwó láì kun nkankan sí ojú ní ojó èye rè .

  Èyin òdóbìnrin ; njé èyin le múra báyìí ní ijó ìgbéyàwó yín bí? Gbogbo obìnrin ni ó máa n gbèrò láti dàbí egbin ní ojó ìgbéyàwó won , gbogbo ònà ni won yóò sì wá láti jékí èróngbà won ...

Read More »
olodumare

Question of the Week !

Olodumare has been called the Supreme God of the Orisa people. A couple of questions arise: Is there a Supreme God, like Yahweh among the Hebrews, among the Orisa people? Or is it more like in the Hindu religion, where ...

Read More »
Yoruba colours

Top 3 Yorùbá Colours – (Yoruba Colour naming Challenge)

A thorough discussion on the Yorùbá color scheme requires a very detailed study of notjust chromatics, but also philosophy, religion and culture as well. It is well beyond theintention of this module to fully explain the basis of the traditional ...

Read More »

Ìgbéyàwó ìbílè ti Oludamilola Osinbajo àti Oluseun Bakare ní Aso Rock.

Ìgbéyàwó ìbílè ti Oludamilola Osinbajo àti Oluseun Bakare ní Aso Rock. Èyí ni àwòrán láti òdò igbákejì Ààre, professor Yemi Osinbajo, omobìnrin rè Oludamilola Osinbajo níbi ìgbéyàwó ìbílè rè èyí tí ó wáyé ní ilé Ààre orílè èdè Nàíjíríà. Igbákejì ...

Read More »
orunmila

Oriki Orunmila (Praise)

Ifá Olókun, A – sorò – dayò, Elérìn-ìpin, Ibìkejì Èdùmàrè. The Diviner of the Sea, the one who makes affairs prosper, Witness to Creation, Second to the Creator. Òrúnmìla ni Baba wa o e, àwa kò ni Oba méjì, Ifá ...

Read More »
oyo empire

THE OYO EMPIRE: Alaafin Aole, Afonja, Alaafin Atiba and the Jihadist

In 1817, Afonja of Morin was the Are-Ona Kakanfo – the Head of the Army of the Oyo Empire, under the Alaafin of Oyo – Aole (The King). That year, Afonja sent an empty calabash to the Alaafin Aole, thereby ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb