Funke Akindele tí gbogbo ayé mò sí Jennifer tún yo ní àrà òtò níbi àwòrán yí…
Read More »Peter Okoye se ayeye ojó ìbí fún Anita Okoye.
Peter Okoye tí ìnagije rè n jé Mr P gbe sí orí èro ayélujára (Instagram) láti se ayeye ojó ìbí ìyàwó èkejì rè . Anita Okoye tí ó lé odún kan ní òní. Ó ko sí ibè wípé ...
Read More »Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí ògá olópàá yí àti ìyàwó rè Hausa yà.
E gbe yèwò àwòrán tí ó rewà kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí ògá olópàá yí àti olorì tí a mò sí Hauwa yà . Won sì se jómírégí.
Read More »Alángbá nlá tí won pa fún obè aláta yéríyérí.
Gégé bí ò n lò èro ayélujára (Facebook) se pin. Ó so wípé òun pa Àntà( Alligator) nláyí ní àárò yí òun sì n wá àwon èlò tí òun yóò fi si láti se obè aláta yéríyérí. È ...
Read More »Àwòrán ìsìnkú Akékòó bìnrin ti ilé-èkó gíga Auchi poly tí àwon figilanté yin ìbon pa. Ódigbéré Ooo Uloko Lawretta Apaume .
Ódigbéré Ooo Uloko Lawretta Apaume . Olóògbé Lawretta ni won pa… Kí olúwa te sí aféfé rere … Kí ó tó di wípé ó kú ó jé Akékòó Banking and Finance HND2(tí ó sèsè kékòó parí) . Olùkó àti ...
Read More »E wo ejò tí aládùúgbò mi pa ní ilé àyágbà rè.
E wo ejò tí aládùúgbò mi pa ní ilé àyágbà rè. O jé kó kúrò ní ilé àyágbé yí.
Read More »Dangote fún àwon tí ó fi ara káásá níbi ìjàmbá iná ní ìlú Kano ní Mílíónú lóna èédégbéta náírà
Dangote fún àwon tí ó fi ara káásá níbi ìjàmbá iná tí ó selè ní ìlú Kano ní Mílíónú lóna èédégbéta náírà(#500,000,000)…
Read More »Aisha El-Rufai se àgbékalè ètò abéré àjesára àti láti lé ìta lo l’ára omodé.
Gégé bí Gómìnà ìpínlé Kaduna se pin, El Rufai. “Aisha El-Rufai ti se àgbékalè abéré àjesára àti ìpolongo láti lé ìta lo l’ára omodé.
Read More »Stephanie Coker tún yo ní àrà òtò, ó tún yanilénu nínú àwòrán tuntun tí ó sèsè yà.
Stephanie Coker tún yo ní àrà òtò, ó tún yanilénu nínú àwòrán tuntun tí ó sèsè yà. Stephanie Coker ti se ìgbéyàwó láìpé ojó, tí a bá ní p’aró ìgbéyàwó náà ye é…
Read More »Àwòrán tí ó yanilénu tí Hailey Adeleke yà.
Omobìnrin kejì ti gbajúgbajà olórin ní orílè èdè Nàijíríà , Davido , omo tí kò tíì fi esè kan ilè baba rè rí, ni ó ti n dàgbà sínú ewà , ó ti è ti rewà jù nínú àwòrán ...
Read More »