Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwon egbé òkùnkùn Badoo ti pa Ebí tí ó jé méta ní Epe ní ìpínlè Eko .

Àwon egbé òkùnkùn Badoo ti pa Ebí tí ó jé méta ní Epe ní ìpínlè Eko .

Àwon omo egbé òkùnkùn tí pa ebí tí ó jé méta tí won sì fi omo kékeré tí ó fi ara pa sílè ní Epe ní ìpínlè Eko. Won ti pa gbogbo ìdílé kan run sùgbón won fi omo kékeré kan tí ó pa l’ára gan sílè ní Epe ní ìpínlè Eko láìpé yí.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

taniolohun

Esin Ajeji Pelu Ete