Òdómobìnrin odún mókàndínlógún tí ó tún jé ò n lò èro ayárabíàsá (Twitter) ti gba àwon òdóbìnrin ní ìmòràn wípé kí won múra sísé kí won sì gbàgbó nípa èróngbà olórun sí won nígbà tí ó n ...
Read More »Òdómokùnrin kan ní orílè-èdè Ghana ni ó pa ara rè látàrí wípé àwon ebí rè kò gbà kí ó fé ìyá omo rè .
Òdómokùrin kan ni orílè-èdè Ghana ni ó pa ara rè léyìn ojó díè tí ó pín nípa àwon ebí rè tí kò gbà fun kí ó fé ìyá omo rè….
Read More »Nneoma Nkechi àti Rochas Okorocha pín àwòrán won tí ó ti pé .
E wo àwòrán tipétipé Gómìnà Rochas Okorocha àti ìyàwó rè tí ó rewà, Nneoma Nkechi Rochas Okorocha. Àgbà wá búra bí èwe ò bá se ó rí…
Read More »Àwòrán ìgbéyàwó ògbóntarigì olórin afòròdárà tí orúko rè n jé Gucci mane .
Àfòròdárà (Rapper) Gucci Mane àti Keyshia Ka’oir se ìgbéyàwó alárinrin tí ó jé wípé ogún-l’ógbòn àwon ènìyàn ni won wò ó n’ílé l’óko lórí èro amóhùnmáwòrán.igbéyàwó náà rinlè gan tí ó fi jé wípé àwon ènìyàn jàkànjàkàn ...
Read More »Omoge kan ni owó tè tí won sì fi se èsín látárí wípé ó fo odi ilé onílé láti jí bisikitì .
Ònlò èro ayélujárá ( Facebook) tí a mò sí Arc Pashal Chike Umeobi ló so wípé arábìnrin yí ni owó àwon figilanté tè ní Ezinifite , ìlú kan ní ìpínlè Anambra . Arábìnrin yí ni won fi ...
Read More »Omokùnrin Wizkid , Ayo kékeré òun àti ìyá rè múra jáde nínú aso orílé èdè Nàíjíríà .
Binta Diallo àti omokùrin rè ,king Ayo kékeré jáde lo láìpé tí won sì tàn gan nínú Dashiki won àti aso orílè èdè Nàíjíríà. Aso orílè èdè Nàíjíríà yí jé kí ó dà bi omo Yorùbá tí ó ...
Read More »Nígbà tí adékódère bá padà s’ábúlé .
Òpò omoge òde-ìwòyé ni a bí sí abúlé sùgbón bí won bá ti jáde díè ìwà àti ìsesí won yóò y’àtò, won á sì gbàgbé orísun won. ...
Read More »Ejò tí mo pa nínú ilé Adìe mi lóòní.
Ní òní mo gbèrò láti tún ilé àti àyíká Adìe mi se, ni mo pàdé afayàfà yí, mo sá eré bí mo se le sa mo. Nítorí ìgbà àkókò mi rè é tí mà rí ejò ńlá báyìí láàyè, tí ...
Read More »Ogún-l’ógbòn àwon baba ńlá ìran yorùba l’ójé alágbára, lára won ni *Timi Àgbàlé olófà iná*.
Timi Àgbàlé, olóde tí ó sì jé jagunjagun tí Aláàfin rán lo sí ìlú Ede láti dáàbò bo àwon ènìyàn ibè. Alágbára ènìyàn ni Timi jé , tí a sì mò ó sí *Timi Àgbàlé olófà-iná*,gégé bí ìtàn se so, ...
Read More »Alaafin decries attack on Yoruba culture by Islam & Christianity
By Daud Olatunji ABEOKUTA — The Alaafin of Oyo, Oba Lamidi Adeyemi, yesterday, raised the alarm over the erosion of Yoruba culture by what he called received religions of Islam and Christianity. Oba Adeyemi, Alaafin of Oyo The first class ...
Read More »