Home / Art / Àṣà Oòduà / Ebube Nwagbo fi enu ko eja nlá tí ó n jé Dolphin ní Dubai fún ìsinmi.

Ebube Nwagbo fi enu ko eja nlá tí ó n jé Dolphin ní Dubai fún ìsinmi.

Òsèré Ebube Nwagbo tí ó wà ní ìsinmi lówólówó ní Dubai ti pin sí orí èro ayélujára (Instagram) àwòrán aso ìwè rè pèlú bí ó se n wè l’ódò àti eja nlá tí ó n jé Dolphin .

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

Ọdún orò gbìnà yá, ìdájí ní àwọn olórò yóò fi máa yíde ìlú níṣẹ̀yin

Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe aifẹsọ kebosi,lai rẹni jo o,ati pe n ta o ba fẹ o bajẹ,o ni bi o ṣe yẹ ka ṣe e,eyi lo bi atunse abẹnu lati fopin sawuye wuye to waye latari aawọ to suyọ laarin awọn onisese ati awọn ẹlẹsin meji ti o ku(Kitẹẹni ati Musulumi).Wayi o, igbakeji alaga fun ẹgbẹ agbaagba nilu Isẹyin, Alhaji Bọlaji Kareem, ti kede pe ija ti dopin, ogun si ti tan lori aawọ ọrọ sise nilu Isẹyin.Kareem, ẹni to soju ...