Awon omo egbe apapo-Yorùbá-titi eka –oselu, Afenifere ati awọn omo egeb (Oodua Peoples Congress), OPC, ti fariga nipa rogbodiyan ti oun lo ni ilu Ile Ife. Ninu oro kan ti abenugo fun eggbe Afenifere kán so eyi ti un se ...
Read More »Ti eba jabo si inu omi pelo ọkọ ayọkẹlẹ: Eleyi ni ona irọrun ti elefi gba emi yin la (Fidio)
Eleyi ni ona irọrun ti elefi gba emi yin la, ati ligba ti eba jabo si nu omi eyin ati ọkọ ayọkẹlẹ yin. A se iwadi wipe egbelegbe irinwo “400” awon eniyan ni ounku ni ododun lipa ijamba awon ati ...
Read More »Tani Obalufon Ati Kini Ojuse Re?
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun ku imura toni eledumare ninu aanu re koni jeki a we ninu agbara eje bi a se njade lo loni o ase. Laaro yi mo fe se ...
Read More »Posita gbigba okore pada Kun ilu Port-Harcourt Egba ni eleja
Posita wagba okore kun igboro ilu Port-Harcourt
Read More »Eyin eniyan e wo E-moni(E-money) ninu photo titun re.
Alaga ti Ẹgbẹ eka marun apapo , wuni ninu poto re titun ti o sese ya.
Read More »Tonto Dikeh ki Mercy Johnson pe ‘oku orire fun ipo titun ti Gomina Kogi sese yan si’.
Awuyewuye ija ti oun lo laarin awọn oṣere Tonto Dikeh ati Mercy Johnson, Tonto Dikeh ti toro aforiji lori awọn gbólóhùn o ṣe nipa ọmọ rẹ ati awon oro miran to ti so ni odun die seyin. Mercy Johnson gba ebe ...
Read More »Aseritu: Awon Agbofinro ‘SON’ Ri Ile Alaja Meji Ti Won Ko Ogun Ti O Ti Ba Je Si. (Aworan)
Awon ‘SON’ (Standards Organisation of Nigeria) ti mu ogbeni akeruwole ti oun ta aye deru Kosimetik ati ọti-waini ti se ayipada awọn ogun ti ọjọ ti lo lori wọn ati ti o nri titun ọjọ lori wọn, ni eyi ti ...
Read More »Ẹ̀rù ló sọ ọmọ Ẹkùn di Ológbò/Ológìní tó fi di ” Ẹran-àmúsìn – Ọdẹ peku-peku” –
Ni igbà àtijọ́, ẹranko ti wọn pè ni Ẹkùn jẹ alágbára ẹranko, bẹni Kìnìún si jẹ́ alágbára ẹranko. Bi Kìnìún ti lágbára tó ninú igbó, bi ó bá bú ramúramù, ohun gbogbo ninú igbó á pa kẹ́kẹ́ titi dé ori ...
Read More »“Àṣejù Baba Àṣetẹ́” – Ìtàn bi Ojúkòkòrò àti Ìgbéraga ti jẹ́ Àṣejù
Ni ìgbà àtijọ́, ọkùnrin kan wa ti orúkọ rẹ njẹ́ Ìgbéraga. Wọ́n bi Ìgbéraga si ilé olórogún, àwọn ìyàwó bàbá́ rẹ yoku ni ó tọ nitori ìyá rẹ kú nigbati ó wà ni kékeré. Lẹhin ti o tiraka lati pari ...
Read More »Omo Yo’ooba: Se Looto Ni?
Se beeni abi be ko ?
Read More »