Àwon omo ebí mérin ti igbákejì adarí kíko eré ìdárayá ní orílè èdè Nàìjíríà ” Vice President of Sport Association (SWAN), Eddie Bekom tí a gbà sí ilé-ìwòsàn léyìn ìgbà tí gáàsì tí wón fi ń dáná bú gbàmù láti ...
Read More »
ayangalu Comments Off on Gáàsì bú gbàmù ní Cross river tí ó sì pa èèyàn méji, tí ó fa ìpalára fún àwon mérin nínú ebí.
Àwon omo ebí mérin ti igbákejì adarí kíko eré ìdárayá ní orílè èdè Nàìjíríà ” Vice President of Sport Association (SWAN), Eddie Bekom tí a gbà sí ilé-ìwòsàn léyìn ìgbà tí gáàsì tí wón fi ń dáná bú gbàmù láti ...
Read More »ayangalu Comments Off on Yakubu Gowon lo kí Shehu Shagari.
Olórí ìpínlè télè (former head of state) General Yakubu Gowon lo kí Ààre ti télè Shehu Shagari ní ilé rè ní Sokoto. Gómìnà Tambuwal sìn-ín lo pèlú Olórí àlùfáà Ìjo Catholic ti Sokoto, Bishop Matthew Hassan kukan àti àwon ènìyàn ...
Read More »ayangalu Comments Off on Annie Idibia da padà fún olùtèlé rè tí ó pè é ní omobìnrin tó “wor wor “.
Annie Idibia fi àwòrán yí sí orí èro ayélujàra rè (instagram) tí ó rò wípé kò rewà pè é ní omobìnrin tó ” wor wor ” . Ìyá omo méji tí òhun náà sì da padà fun pé :bí ìyá ...
Read More »ayangalu Comments Off on Falz àti 9ice je oúnje alé papò (àwòrán, fídíò).
Falz ti fi èsì àìgbó ra eni ye hàn láàrin òun àti 9ice nígbà tí òpò rò wípé 9ice ni ó ń báwí nígbà tí ó ń gba àwon olórin ní ìmòràn kí won má fi Orin yin àwon gbájúè ...
Read More »Lolade Comments Off on Olúbàdàn kìlò kí won má se jàgídíjàgan bí odún egúngún se fé bèrè.
Gégé bí odún egúngún odoodún se ma bèrè l’óla, ojó ajé, ní ìlú Ibadan, ní ìpínlè Oyo, Olúbàdàn ti ilè Ibadan, oba Saliu Akanmu Adetunji ti pè fún àláfíà láti òdò àwon eléégún àti àwon tí ó ń tèle tí ...
Read More »Lolade Comments Off on Àwòrán láti ìlú olómìnira kan tí a mò sí Ewédú àti ìgbálè
Àwòrán láti owó omo oòduà rere. Àwòrán láti ìlú olómìnira kan tí a mò sí Ewédú àti ìgbálè (a fé béè, èrín yakata). Ta ló tún n’ìfé àwòrán láti ìjìnlè ìlú yorùba? N’ísàlè ni àwòrán àjò lo sí ìlú Iseyin ...
Read More »BalogunAdesina Comments Off on Hundreds of artists mock Trump in Tehran cartoon competition
BalogunAdesina Comments Off on Trumponium and Putinita?!
ayangalu Comments Off on Between Alaafin & Elders Of Yoruba Religion Over Oba Ifa Adimula Of S. America Title
Elders of Traditional Religion worshipers under the aegis of the Concerned Committee of Yoruba Traditional Culture and Faith Ambassadors have stood in defence of three Ifa priests accused of impersonating the Alaafin of Oyo, Oba Lamidi Adeyemi, and extorting some ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àwòrán : afurasí omo egbé òkùnkùn kan tí a mò sí Baddo ni owó tè ní Ikorodu.
Afurasí omo ògbó-n-tarìgì egbé òkùnkùn, Baddo, ni owó tè ní Ikorodu ní ìpínlè Èkó Lánàá tí osù kefà di ogbòn (June 30th) gégé bí àwon olùgbé àdúgbò se so, a rí Arákùnrin yí tí ó ń rìn káàkiri agbègbè Obafemi ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more