Iree! Apa mejeeji l’eyele fi n ko’ree wo’le. Ire otun, ire osi, ire niwa, ire l’eyin, ire Olokun, ire Olosa, ko mi a da giriri wole to wa wa! Aase!
Read More »Idile Alayo Toni 09.06.2016
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. ...
Read More »Odo Iwoyi – 3
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. ...
Read More »Sun re O! Henrietta Kosoko
Hummmmmm Erin wo ajanaku tisun bi Oke eyin ka ile Erin wo porogodo,okoko fo omi okoko danu haaaa sebi eyan Se nku re Oga oooo…….Orun mo kanju Ojo eda oni se ooo
Read More »#OkeItase2016! Preparation of the World Ikin
Ikin ifa agbaye/world ifa sacred palm but…we dem boys getting it ready for the festival… Yay??? See more photos after the page break
Read More »E fu’n Foto yii ni Oruko
E daku’n e be wa fu’n foto yii ni Oruko ka’n to dara!
Read More »A ku ojumo oooooooo!
Oba to silekun ojo oni, yoo sina ayo fun wa, yoo sina aje fun wa, A ko no seru egbe wa, ire ayo wa ko ni fo wa ru(Ase). #AKARA_IMORAN : Ma se gbo oro okere, gbiyanju lati wadi ohun ...
Read More »Gbiyanju lati toju obi i re !
Ojumo to mo wa lonii, ojumo ibukun, ojumo igbega, ojumo aseyori, ojumo ire, ojumo itunu, ojumo ayo, ojumo idunnu ni yoo je fun gbogbo wa lase Edumare(Ase). # AKARA IMORAN : Gbiyanju lati toju obi i re, niwon igba ti obi ...
Read More »Llegando a oke igeti home de Orunmila.
Foto kerediti –
Read More »Obara Oturupon/Obara Tiele Corpus by Ifa Chief Priest
Good morning my people, how was your night? Hope it was enjoyed. I wish you all happy new month, may this month bring us everlasting joy and happiness amen. It is OBARA OTURUPON/ OBARA TIELE corpus that revealed this morning, ...
Read More »