E MAA WI TELE MI : ….. *Fitila ogo mi ko ni ku. *Aso iponju ko ni se dede orun mi. *Oluwa ba mi segun ota ile. *Edumare ba mi segun ota ode. *Ina omo ko ni jo mi. *Ina ...
Read More »Aku ojumo lokun !
Lobinrin wa se dada laji bii.. Adupe lowo OLODUMARE too mu emi ati iwo losii ipo oku lati ano too tun jiwa pada saiye, si aye rere nitori gbogbo eni bati sun ti oku ope ni fun ODUMARE.. Moo wa ...
Read More »State of Mind…
One of the terracotta dug out from Ita Yemoo at Ile Ife in the 1900s by Leo Frobenius
Read More »Ogulutu Oro Toni: 08.05.2016
Hummm wo oremi banuso mobayan so tori inu jin. # wo Opolopo ore lo nfara han gegebi ota Oplopo ota naa losi nfi ara han gegebi ore….. # nje Otie mo pe opo alangba lo dankun dele ao kuku mo ...
Read More »Iki’Ni Fun Ayeye Ojo Awon Iya Wa
ORIN : “E bami KIRA fun #Mama mi.. #Orisa bi #IYA o.. Ko si Laye… …………….. Iya mi.. Abiyamo lojo Ogun le.. Abiyamo Oloja Aran Abiyamo tii fojooumo wa ko le Dara fun Omo… …………………… Ki Emi gbogbo Awon #IYA ...
Read More »Iwure Owuro: 08.05.2016
E MAA WI TELE MI : …….. *Oluwa gba eru iya lori mi. *Edumare ma se je ki n seru egbe. *Oluwa taari alaanu si mi. *Edumare fiso re so mi. *Oluwa pase irorun sinu aye mi. *Iku aitojo ko ...
Read More »Sun re o: Francis Aiyegbeni alase ‘D’Rovans Hotel’ ni ibadan
ojuluoooooooo! owe ni oro-aye, A NLO SI OYO O KOJU SI OYO A TUN BO LATI OYO OYO NAN LO TUN KOJU SI. SE BI ILU-GANGAN. iyen nipe ORUN LATI WA ORUN NAN LAO PADA SI. iku pa ABIRI o ...
Read More »Tani arakunrin-olokada yi jo ?
Kabiesi re Edua! a se otito ni oro awon agba to sope mejimeji ni Eledua da eniyan. OUN TO BA JO(resemble) OUN LA FI WE ARAWON EPO-EPA JO POSI ELIRI OWO-ALABAUN JO HANHAN-OPE. tani arakunrin-olokada yi jo(resemble)?
Read More »Ogulutu Oro Toni
Igbiyanju loma ngbeni de ipo ola Igbiyanju loma njeki kadara o se # wo Oremi masinmi igbiyanju oo ki o le dele ileri Majeki isoro kisoro kopa okanre da Lori ipinu ayo re Tepa mose re loni Ki osi mo ...
Read More »Iwure Owuro – 05.07.2016
E MAA WI TELE MI : …….. *Edumare ma se je ki n fi ota s’ore. *Oluwa gba mi lowo afoju-feni ma fokan-feni. *Edumare gbe mi leke abinu eni. *Oluwa ma se je ki n je egungun kehin eran. *Edumare ...
Read More »