Home / Art (page 209)
Sunkanmi lori eto Gbajumo Osere
Biodun Okeowo lori eto Gbajumo Osere
Ara lori eto Gbajumo Osere
Ajisa lori eto Gbajumo Osere
Nje toba jepe Eyin Ni arakunrin yi
Kilerope Elese Fun Iru nusi bayi ?
Read More »Oro Sunuku
Moki gbogbo wa ku ise oni, asejere ni gbogbo wa yoo se lagbara Eledua ase. Eyi ni lati fi to gbogbo a wa ololufe eto yii leti wipe, gbakogbi itan akakogbon ti a npo po ti di itan agbeleka fun ...
Read More »Oro Sunku: Ore Mi, Iran Keji
-Sola:. ( O wole, o kumle si egbe ibusun Baba ati Iya re) E jowo, mo nilo owo nile eko ni. Won fun wa ni ise asatilewa kan ni, yoo si na mi to egberun marun naira. -Baba Sola:. Ha! ...
Read More »E jo kilo kun ki arakunrin yi fi si obe yi ko ba le dun dada
Edaku, e fun foto yi ni Oruka kan ?
Read More »Oro Sunku: Ore Mi, Iran Kerin
(Ni nnkan bi aago meje irole ni ibugbe awon obinrin ni ogba Yunifasiti, ero po nibe lokunrin lobinrin. Awon kan n wole, awon kan n jade. Awon okunrin miiran wa ninu oko ayokele pelu awon omoge, won n soro. Awon ...
Read More »