Home / Art (page 223)

Art

agba

Art of the Day: Àgbá

Artist: Undocumented Yoruba artist. Title: Àgbá Medium: wood, hide, pigments. Date: lost Agba’ just like edi-iwori speak:edi gbagbagba, iwo jegejege adifa fun agba to nlo re ka olomo

Read More »
ifa rule

AṢẸ: Irosun di awo ẹlẹtà ádífá fun ẹlẹtá eyi..

Irosun di awo ẹlẹtà ádífá fun ẹlẹtá eyi tin se owun gbogbo ti ikan ko lori (wọn ni ẹbọ nikose..orùbọ tan lowa di oni re gbogbo) Njẹ ori ẹni ni awure, eníyan bí ẹbáá ji lowurọ kí ẹdí ẹlẹ́da yin ...

Read More »

IROYIN OWURO ose yii ti jade oooooooo

Ese ‘o gbero ni Ikenne Paradise ni mama wa bayi – Pst Adeboye Opelope Mama Kapenta nii nba je – Pst Bakare Okunrin to feran ibalopo pelu okunrin farahan ni Abeokuta Oju to maa ti awon ti won nbu ijoba ...

Read More »

Oga olopaa yari ooo

Kosi ohun teeyan ko ni ri tan ni Naija yii sa. lol

Read More »
Akintunde Ayeni

“Gbajue paraku ni Dokita Akintunde Ayeni” -Onibara Yem-Kem lo so bee

Arabirin Bamidele Ademola-Olateju lo gbe atejade kan sori ero FACEBOOK re nipa alase Yem-Kem International, Dokita Akintunde Ayeni. O ni gbajue paraku ni  maanu naa. Ohun ti arabirin Bamidele tun wa fi kun un ni wi pe,  Dokita Akintunde ti ...

Read More »
fayose

Fayose niso eleja

E tun gbe yewo, Gomina Foyose tun gbe sunmo iya eleja.

Read More »
solande

Oba’binrin Asa Solaade Iyaasa: Ohun IFA ati Iwure

ÒÒṢÀ ÒKÈ, ÌBÀ IFA ni ti a ba ji a ki OLU OLU moji mo ki o loni IFA ni to a ba ji a ki Osin, osin moji mo ki o loni ELA ni kan ni somo bibi inu ...

Read More »
omo ambode

Omo Gomina Ambode n je igbaladun Sande lowo

Kosi ise lonii ojo Sande l’Alausa. Ile ni Habib Aruna, akowe iroyin fun gomina Akinwunmi Ambode, wa pelu aya re. Awon mejeeji jo n je igbaladun ara won loni miliki.Ki lo tile kan mi na lori oro oko ati iyawo ...

Read More »
Kunle Afolayan

Awon Foto Kunle Afolayan niluu Kenya

Die ni yii ninu ibudo ere fiimu tuntun Kunle Afolayan, The CEO, ni ilu Nairobi to wa ni Kenya.

Read More »

E wo ohun ti won so nipa Basiru Alaaru niluu Abuja

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb