Aare Muhammadu Buhari ti bale ni Tehran to wa ni orileede Iran nibi ti yoo ti maa joko se ipade eleeketa iru e ti egbe awon orileede ti n gbe epo robi jade fun awon orileede agbaye.
Read More »Saraki gba Basketmouth lalejo niluu Abuja
Aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, gba Basketmouth lalejo ninu ile re to wa niluu Abuja
Read More »Adanwo ni oro ile aye: Iku Abubakar Audu gba arojinle
Titi di akoko yii, enikeni ko le so pato ohun to sekupa oludije ipo gomina labe egbe oselu APC ni ipinle Kogi, Abubakar Audu. Se ise aye ni abi amuwa Olorun oba? Ohun ti ko ye enikan, kedere ni niwaju ...
Read More »Awon akekoo LASU yari, won ni awon alase n ko leta si yanponyanrin
Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa Awon omo egbe akekoo Ifafiti tilu Eko, Lagos State University Students Union (LASUSU) ti bere si ni fariga pelu ifehonuhan latari bi awon alase ileewe naa se fi owo kun owo igbaniwole awon akekoo tuntun. Ifehonuhan ...
Read More »“Idagbasoke awon akonimoogba gbodo je koko fun NFF” – Amodu
Shuaibu Amodu, okan lara awon igbimo oludari ajo NFF ti so wi pe ona kan pataki lati se igbelaruge fun ere boolu alafesegba abele ni nipa sise eto idagbasoke fun awon akonimoogba ere boolu ile Naijiria. Oro yii ni Amodu, ...
Read More »“Ijoba APC gbodo je ki eto eko ofe rinle de ileewe giga” – Atiku
Igbakeji Aare ile Naijiria nigba kan ri, Alaaji Atiku Abubakar ti ro ijoba to wa lode yii, eleyii to wa lowo egbe oselu APC, lati je ki eto eko ofe ti won se ileri re kari gbogbo eka ikekoo patapata, ...
Read More »Won gun pasito ijo RCCG lobe niluu Ota
Edward Campbell, eni odun mokandinlaadota (49) ni won ti gbe lo si ile ejo lojo Eti to koja yii pelu esun wi pe o gun pasito Redeemed Christian Church of God (RCCG), Dotun Olojede, lo be. Ile ejo Majisireeti to ...
Read More »Ijamba buruku kan lo waye loju ona masose Ilesa si Ibadan
Awon Yoruba bo, won ni iku ti o ba pani, toba si fila eni lo ope ni ka maa du. Ijamba buruku kan lo waye loju ona masose Ilesa si Ibadan l’Ojobo ose to koja yii nigba ti maalu awon ...
Read More »Simisola Omoayan: Omidan ti n filu dara
O ti wa daju wi pe kosi oun ti okunrin se ti obirin o le se. Bi eniyan ba si foju kere ata, afaimo ki iru eni bee ma kabamo leyin oro. Eni Edua Oke ba fe ni i fun ...
Read More »Otun Olubadan tile Ibadan ti dagbere faye
Otun Olubadan ti ile Ibadan, to tun je okan pataki ninu awon agba oye ile Ibadan, Omowale Kuye, ti dagbere faye leni odun metadinlaadorun (87). Oloye yii la gbo wi pe o dake ninu ile re to wa ni agbegbe Ikolaba ...
Read More »