Iroyin yajo-yajo to sare wole yii lo n salaye wi pe arabirin Jessica Elvis to je olori egbe awon asewo, oninabi ile Naijiria ti rekoja lo sorun.
Read More »Asiri Tony Blair ati George Bush tu: Blair ti lo toro aforojin ni ti e
Olootu ile Biritiko nigba kan ri, Tony Blair, ti toro aforojin lowo gbogbo aye pelu bose lediapopo mo ijoba ile Amerika eleyii ti George Bush se adari fun lati fogun ja ile Iraq. Alaye yii ni Ogbeni Tony se lori ...
Read More »Foto: Davido se baba gidi fomo re
Sebi tori omo naa la se n sise… Omoomo baba olowo
Read More »Won ti yan Ooni tuntun ni Ile-Ife
Awon afobaje ilu Ile-Ife ti yan Omooba Adeyeye Enitan Ogunwusi lati idile Giesi gege bi Ooni tuntun bayii. Won si ti fi oruko oba tuntun naa ranse si gomina ipinle Osun, ogbeni Rauf Aregbesola.
Read More »Mama o fe e gba: Iyabo Ojo ati omo re
Edumare ma pa omo folomo. Ti eniyan ba ri omo Iyabo Ojo, eniyan le sebi boya aburo re ni. Iya gan-an ni ko si fe gba yii. Oga ju!
Read More »Photos: Check out an Igbo village built in Virginia, USA!
The Igbo town is situated in Staunton, Virginia, USA. As indicated by one of the coordinators Basil Okafor, “The State of Virginia and US government recognize the Igbos as one of the early slaves who settled in Virginia.” See more ...
Read More »Photos: Meet the New Ooni Of Ife, Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi (Kabiyesi O)
ki Ade ko pe lori ki Bata pe lese o,Kabiyesi o.. Adeyeye Enitan Ogunwusi from the Geisi ruling house has been unveiled as the new Ooni of Ife. Moshood Adeoti, secretary to the Osun state government, confirmed this in an ...
Read More »Madueke ko ti bo ninu ejo, Ile ejo ko fun Saraki nisimi, Abba Moro tun ko sowo EFCC
Madueke o ti bo ninu ejo, Ile ejo o fun Saraki nisimi, Abba Moro tun ko sowo EFCC Olayemi Olatilewa Ile ise ti n risi iwa idaran niluu London, National Crime Agency [NCA] si n ba iwadii won lo ni ...
Read More »Won ti gbe oye Dokita fun Oba Lamidi Adeyemi III
Leyin ayeye ojo ibi odun metadinlogorin (77) Oba Lamidi Olayiwola Atanda Adeyemi III to waye laipe yii, awon ojongbon tun ti pawopo fi oye Dokita da Alaafin Oyo lola. Ayeye yii lo waye l’Ojoru to koja yii nibi won ti ...
Read More »Olise dubule aisan leyin ti Emmanuel Emenike dagbere fun egbe Super Eagles
Akoni-moogba egbe agbaboolu Naijiria, Sunday Oliseh ni won ti gbe digbadigba lo si ilu Belgium bayii fun itoju. Ajo ti n dari ere boolu Naijiria, The Nigeria Football Federation lo so eleyii di mimo loju opo won [@thenff] eleyii to ...
Read More »