Shuaibu Amodu, okan lara awon igbimo oludari ajo NFF ti so wi pe ona kan pataki lati se igbelaruge fun ere boolu alafesegba abele ni nipa sise eto idagbasoke fun awon akonimoogba ere boolu ile Naijiria. Oro yii ni Amodu, ...
Read More »
admin Comments Off on “Idagbasoke awon akonimoogba gbodo je koko fun NFF” – Amodu
Shuaibu Amodu, okan lara awon igbimo oludari ajo NFF ti so wi pe ona kan pataki lati se igbelaruge fun ere boolu alafesegba abele ni nipa sise eto idagbasoke fun awon akonimoogba ere boolu ile Naijiria. Oro yii ni Amodu, ...
Read More »admin Comments Off on “Ijoba APC gbodo je ki eto eko ofe rinle de ileewe giga” – Atiku
Igbakeji Aare ile Naijiria nigba kan ri, Alaaji Atiku Abubakar ti ro ijoba to wa lode yii, eleyii to wa lowo egbe oselu APC, lati je ki eto eko ofe ti won se ileri re kari gbogbo eka ikekoo patapata, ...
Read More »admin Comments Off on Won gun pasito ijo RCCG lobe niluu Ota
Edward Campbell, eni odun mokandinlaadota (49) ni won ti gbe lo si ile ejo lojo Eti to koja yii pelu esun wi pe o gun pasito Redeemed Christian Church of God (RCCG), Dotun Olojede, lo be. Ile ejo Majisireeti to ...
Read More »admin Comments Off on Ijamba buruku kan lo waye loju ona masose Ilesa si Ibadan
Awon Yoruba bo, won ni iku ti o ba pani, toba si fila eni lo ope ni ka maa du. Ijamba buruku kan lo waye loju ona masose Ilesa si Ibadan l’Ojobo ose to koja yii nigba ti maalu awon ...
Read More »admin Comments Off on Simisola Omoayan: Omidan ti n filu dara
O ti wa daju wi pe kosi oun ti okunrin se ti obirin o le se. Bi eniyan ba si foju kere ata, afaimo ki iru eni bee ma kabamo leyin oro. Eni Edua Oke ba fe ni i fun ...
Read More »admin Comments Off on Otun Olubadan tile Ibadan ti dagbere faye
Otun Olubadan ti ile Ibadan, to tun je okan pataki ninu awon agba oye ile Ibadan, Omowale Kuye, ti dagbere faye leni odun metadinlaadorun (87). Oloye yii la gbo wi pe o dake ninu ile re to wa ni agbegbe Ikolaba ...
Read More »Eleyii tun gaju!
Read More »admin Comments Off on E wo ohun ti won fi ibeji da lara
Nje e le biliifu eleyii? Awon ibeji okunrin meji fe awon ibeji obirin kan naa. Awon pasito meji to so won po, ibeji ni won. Awon ore iyawo meji to tele won, ibeji ni won. Awon omo iyawo obirin, ibeji ...
Read More »admin Comments Off on Inu fiimu wo ni aworan yii ti jade?
admin Comments Off on Yeepa! Mercy Aigbe di Sulia Ayetoro
Sulia kan, Mercy kan, Walahai Ayetoro kan ni
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more