Laide Bakare ti pada si lo n se esesaisi lati pada ri bi omidan, se e mo wi pe awon obirin kii fe darugbo kiakian, ka to wa so wi pe osere. Bakan naa ni awon onise tiata kii fe ...
Read More »
admin Comments Off on Ohun ti Laide Bakare gbe soke ko daa rara
Laide Bakare ti pada si lo n se esesaisi lati pada ri bi omidan, se e mo wi pe awon obirin kii fe darugbo kiakian, ka to wa so wi pe osere. Bakan naa ni awon onise tiata kii fe ...
Read More »admin Comments Off on Awon wo ni Kunle Afolayan sepe fun?
Ogbontarigi onise tiata, Kunle Afolayan ti fepe ranse fun awon ti kii ra ojulowo fiimu ti won se sita, to je wi pe ayederu ti awon onisedudu n se ni won ra. “To o ba ra ayederu sinima mi tabi ...
Read More »admin Comments Off on “Ile ise MTN le kogba wole ti won ba sawon itanran tijoba pase re” – Minisita
Minisita tuntun fun eto ibanisoro, Ogbeni Bayo Shittu ti so wi pe ile ise MTN eka ti orileede Naijiria le kogba wo le ti won ba san owo itanran ti ajo ti n risi eto ibanisoro, Nigerian Communications Commission (NCC) ...
Read More »admin Comments Off on Opin ti de ba ogbologbo olosa ti n gbe alabahun saya jale
Opin ti de ba ogbologbo olosa ti n gbe alabahun saya jale Olayemi OlatilewaOwo awon olopaa digboluja ti a mo si Special Anti Robbery Squad (SARS) ti ipinle Kogi ti te ogbologbo olori awon adigunjale afurasi kan ti n lo ...
Read More »admin Comments Off on Deji Akure ti won yo loye ti gbe Ijoba ipinle Ondo lo sile ejo
Leyin odun marun-un ti ijoba ipinle Ondo ro Adesina Adepoju loye gege bi Deji tilu Akure, oba ilu Akure nigba kan ri naa ti gbe ejo dide ni kootu lati gba ade re pada. Ojo kewaa osu kefa odun 2010 ...
Read More »admin Comments Off on Awon Obirin to n binu si oludari CRIN niluu Ibadan bora sile nihoho
Awon Obirin to n binu si oludari CRIN niluu Ibadan bora sile nihoho Olayemi Olatilewa Gbegede gbina niluu Ibadan lojo Monde to koja yii nigba ti awon osise ibudo imo ti won ti n sewadii ijinle nipa koko, Cocoa Research ...
Read More »admin Comments Off on Atelewo ni mo bala
Ki n to so die fun yin lara itan igbesi aye mi kan ti mi o le gbagbe laelae. Se e ko gbagbe alaye ti mo se fun yin lose to koja? Lara ona ti eniyan le fi se se ...
Read More »admin Comments Off on “Ise aye lo mu mi fadi omo odun meji ya”- Okunrin eni aadota odun (50) lo so bee
“Ise aye lo mu mi fadi omo odun meji ya”- Okunrin eni aadota odun (50) lo so bee Olayemi OlatilewaOkon Michael, eni aadota odun (50) to fi tipatipa fadi omobrin eni odun meji (2) ya perepere ni ipinle Akwa Ibom ...
Read More »admin Comments Off on Se atunbotan aye ti de ba Madueke ni?
Foto tuntun Diezani Allison-Madueke ni yii, minisita fun epo robi nigba kan ri, eni ti won fesun jegudujera kan niluu London. Won ni ara madaamu naa ko ya rara. Joojumo si ni ipo ilera re n buru sii. Arabirin naa ...
Read More »admin Comments Off on Enikan ti Buhari gbagbe lati fun ni ipo misita
Ohun ti Ogbeni Yanju Adegboyega ko nipa maanu naa ni yii: “Walaaahi! Mo sese gbagbo loooto ni pe, alaimoore lo po julo ninu awon oloselu. Olorun n gbo, alaimoore ni Aare Buhari ati egbe oselu APC. Eyin o gbagbo? O ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more