Diepreye Alamieyeseigha, to je gomina ipinle Bayelsa nigba kan ri, ti jade laye leni odun mejilelogota (62) lana Satide. Iroyin to te Olayemi Oniroyin lowo fi ye wa wi pe aisan ejeruru lo pa gomina naa.
Read More »Kayeefi: Adigunjale jabo lati oke aja banki sileele niluu Ilorin
Orisun Okunrin afura si gege bi olosa kan lo jabo lati inu aja ile ifowopamo Guaranty Trust to wa niluu Ilorin lojo Eti to koja (09/10/15). Kayeefi nla lo jo loju gbogbo awon eniyan to wa ninu banki ni akoko ...
Read More »Owo Ba awon igara olosa ti won fi okada sise ole L”Abuja
Owo te awon igara olosa meji kan ti won fi okada jawo gba loju opopona IBB to wa ni agbegbe Maitama niluu Abuja lojo Tuside to koja yii. Ile ifowopamo kan to wa ni opopona IBB ni enikan to je ...
Read More »Ebola seruba awon eniyan niluu Calabar
O kere tan, awon eniyan bi mewaa ni won ti se ayewo fun bayii niluu Calabar latari wi pe won ni ibapade pelu okunrin kan ti won fura si wi pe oseese ko ni arun Ebola. Okunrun ti won fura ...
Read More »Rose Odika setan lati se igbeyawo leyin iya-n-dagbe odun mewaa: Bobo kan lo jamo lowo niluu Eko
Leyin bi odun mewaa ti Rose Odika ti wa gege bi iya-n-dagbe, oserebirin omo Ipinle Delta naa ti setan lati ni oko tuntun. Bi o tile je wi pe bonkele ni won fi oro naa se, ti won si n ...
Read More »Mercy Aigbe pe oko re keji to fe ni adun ife otito: Oko Aigbe pe eni aadota odun laye
Orisun Mercy Aigbe-Gentry, okan ninu awon oserebirin onirawo meje ile Naijiria, dana ayeye ojo ibi to peleke fun oko re, Lanre Gentry, eni to pe omo aadota (50) odun lose to koja. “Eni ma segbeyawo a se gudugudu meje” l’Oritse ...
Read More »Iyawo olopaa gun oko re lobe pa niluu Akure: O ni ise esu ni
Okunrin olopaa kan ti eka ti Ipinle Ondo, Ogbeni Israel Omowa ni iyawo re, Arabirin Wumi Omowa ti gun lobe pa nibi gogongo orun oko re. Ede aiyede kan lo waye laaarin toko-taya ti won gbe ni agbegbe Olu to ...
Read More »Gomina Akinwunmi Ambode gbe ami-eye fun Fasola
Gomina Akinwunmi Ambode ti Ipinle Eko gbe ami-eye fun gomina Ipinle Eko ana, Barisita Babatunde Fasola nibi ayeye weje-wemu olodoodun awon amofin ti Ipinle Eko Gomina Akinwunmi Ambode eni to je alejo pataki nibi ayeye ti won pe ni Legal ...
Read More »Akara Alison-Madueke tu sepo raurau
*O ko sowo olopaa nibi o ti fe fi owo eru ra ile ni London. *Ile ejo gbe ese le owo re mole *Iya re naa ti foju ba ile ejo. *Agbejoro re kede wi pe o ni arun jejere ...
Read More »Iwo taa lo gbeja ninu awon meteeta?
Iwo taa lo gbeja ninu awon meteeta?
Read More »