Ko to di wi pe ma kan lu agbami oselu ti n gbona felifeli bayii ni ilu Spain, nibi ti Arabirin Helen Mukoro to je omo ipinle Delta lati orileede Naijeria ti setan lati dije fun ipo aare orileede Spain, ...
Read More »E Wo Ohun Ti Awon Omo Ile Igbimo Asofin Se Lodun 1962
Awon omo ile igbimo asofin Nigeria ti n foganna lojo to ti pe, ohun ti won se ni yii lodun 1962 nigba rogbodiyan Western Region. Orisun
Read More »Yomi Fash – Lanso N Jaye Oloba Niluu Côte d’Ivoire
YOMI FASH – LANSO Orisun +Wale Ojo-Lanre
Read More »Top 4 Exciting Things About The Fulanis
The Fulanis are amazing people with a rich heritage. The familiar picture of a man from this tribe wielding a stick fending for his priceless cow is a picture that everyone can relate with. This culture of cow rearing is ...
Read More »Oniroyin Meji Ti Wa Ni Kirikiri Bayii: Ise Iroyin Won Lo Ko Ba Won
Alase banki Fidelity ti Nigeria, Ogbeni Nnamdi Okonkwo ni Oniroyin Seun Oloketuyi gbe saye lori ikanni re, www.naijahottestgist.com wi pe oga banki naa feran ko maa se “yodiyodi” fun awon osisebirin banki re. O ni yato si awon osisebirin re, ...
Read More »Iresi Gomina Ayodele Fayose Tun Pada Wo Ipinle Ekiti
Ikere Ektiti ni won ti pin. Atomode atagba, arugbo naa gba ninu iresi Fayose. Ohun ti awon eniyan so nipa re wa nibi:
Read More »Oko Ajagbe Eleru Leyin Jabo Lati Ori Afara Ojuelegba: Emi Awon Eniyan Ba Lo
Oko ajagbe eleru leyin kan jabo lati ori afara to wa ni Ojuelegba niluu Eko losan-an oni. Eniyan meji to wa ninu oko ti ajagbe naa jabo le lori fi ile aye sile loju-ese ti isele naa waye nigba ti ...
Read More »Oriki Ibeji : Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún
Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún. Ẹdúnjobí Ọmọ ẹdun tíí ṣeré orí igi Ọ́-bẹ́-kẹ́ṣé-bẹ́-kàṣà, Ó fẹsẹ̀ méjèèjì bẹ sílé alákìísa; Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá, Tíí gbàdọ̀bálẹ̀ lọ́wọ́ baba tó bí í lọ́mọ. Wínrinwínrin lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ...
Read More »Odaju Abiyamo Fi Ina Jo Omobirin Eni Odun Merindinlogun Loju Ara: O Ni Omo Naa N Se Agbere
Omobirin odaran kan ni owo awon olopaa ti te ni agbegbe Ketu niluu Eko pelu bo se fi ero ayoonu iloso jo omo egbon re ti n gbe pelu re, Bimpe Badmus, omo odun merindinlogun, nidi pelu esun wi pe ...
Read More »Awon Foto Lati Ibi Ijamba Oko Ofurufu Awon Omo Ologun Niluu Kaduna
Awon aworan Oko ofurufu Dornier 228 ti awon omo ologun ile Nigeria ti a kede wi pe o jabo loju orun laaro oni ni yii. Awon eniyan meje ti won wa ninu oko ofurufu naa lo parun patapata.
Read More »