Home / Art (page 261)

Art

Kini kati pe eyi ooo

Read More »

Nje o le daruko ilu kan nile Yoruba to lewa to ilu eko ?

Read More »

Kini toko taya file gbe d’ojo ale

Kini toko taya file gbe d’ojo ale (1) Ife (2) Otito (3) Owo (4) Iro (5) Ibalopo

Read More »

O pari!!!

  -Ibanuje aye e pari loni -Ekun ose aye e pari loni -Ait’egbe aye e pari Lati eni lo -Iya e pari lati oni lo -Asedanu aye e pari lati oni lo -o tun r’arun owo mo lailai -O koni ...

Read More »

Ebami dasi oro yi !!!

Awon okunrin kan wa,nigba tiwon ba un nife Obinrin lowo,won ama se i love,i love u,titi ti obinrin na ma fi de ara si fun won.tiwon bawa ri wipe awon bani ajosepo tan,ti oyun de,won a ba yowo wipe awon ...

Read More »

Iru ere wo gan loyan la yo nigba ewe re ?

Omo Oodua rere ajirebi? Iru ere wo gan loyan la yo nigba ewe re ? (1) Bojuboju (2) Bokoboko (3) Ekun meran (4) Suwe (5) Tete (6) Ere toko ti iyawo

Read More »

Ejowo bawo ni ase le se oro yi ?

Lojo kan mo nlo si ilu keji legbe abule wa emi pelu agbebo adie merin ati agbado abo kan lojiji la de eti odo kan sugbon oloko oju omi ni nko ni anfani lati ko gbogbo awon eru mi lekan ...

Read More »

Eyi ni aworan awon Omo ile iwe ti awon boko haram pa ni ipinle yobe

Eledumare bawa se iku ni isinmi fun won ki OSI ba Wa ro a won obi won lo ju ase awa naa oni fi Ojo olojo lo oooo

Read More »

Ejoo inje oleeto latimalo (CONDOM) fun iyawole?

Ekaro ekuu ojumon ooo. E bami  dahun ibeere yi ! Ejoo inje oleeto latimalo (CONDOM)fun iyawole?

Read More »

Gbolohun kan fun arakurin yi

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb