Ó dìgbà Kehinde Ayoola, Makinde, PDP, APC, ALGON ,ṣe ìdárò akọni Bá a kú làá dère, èèyàn kò sunwọ̀n láàyè.Gómìnà Ṣèyí Mákindé ti sàpèjúwe ọ̀kan lára àwọn Kọmíṣọ́nnà rẹ̀, Kẹhinde Ayọọla tó papòdà ní Ọjọ́bọ, ọjọ́ kẹrìnlá oṣù karùn ún ...
Read More »
ayangalu Comments Off on Ó dìgbà Kehinde Ayoola, Makinde, PDP, APC, ALGON ,ṣe ìdárò akọni
Ó dìgbà Kehinde Ayoola, Makinde, PDP, APC, ALGON ,ṣe ìdárò akọni Bá a kú làá dère, èèyàn kò sunwọ̀n láàyè.Gómìnà Ṣèyí Mákindé ti sàpèjúwe ọ̀kan lára àwọn Kọmíṣọ́nnà rẹ̀, Kẹhinde Ayọọla tó papòdà ní Ọjọ́bọ, ọjọ́ kẹrìnlá oṣù karùn ún ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ewì Toni: Ìwà rere
*Ìwà rere*Iléere ní ẹ̀ṣọ́ nínúÌwà’bàjé ní jẹ́ k’ọ́mọ o j’ìyàẸwúrẹ́ ya aláìgborànÀgùntàn jẹ́ oníwàpẹ̀lẹ́Adígbánnákú ṣẹ̀yìn gákangàkan Iléere ní ẹ̀ṣọ́ nínúÌwà rere lẹ̀sọ́ ènìyànÌwà rere ni òbí ní,tí wọ́n fi ń ǹpé ní òbí rereÒbí rere ló le kọ́mọ ní’wà rereÒbí ...
Read More »Lolade Comments Off on There is traditional cure for COVID-19, says Alaafin
The Alaafin of Oyo, Oba Lamidi Adeyemi, has said there is traditional cure for COVID-19 pandemic. He spoke in his palace while presenting to the public, a book written on the late Yoruba music genre of Apala, Ayinla Wahidi, popularly ...
Read More »ayangalu Comments Off on Èeyàn 239 míràn ni àrùn Covid-19 lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Èeyàn 239 míràn ni àrùn Covid-19 lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà À fi kí Ọlọ́run sàánú wa lórí àjàkálẹ̀ àrùn apinni léèmí kòrónáfairọ̀ọ̀sì yìí tó ń gbomi lójú t’olórí t’ẹlẹ́mù, bí Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí tún kéde àwọn ènìyàn tuntun tó ṣẹ̀ṣẹ̀ kó ...
Read More »ayangalu Comments Off on Kofi 19 dẹ́yẹ sí ìpínlẹ̀ Kogi àti Cross River –Osagie
Kofi 19 dẹ́yẹ sí ìpínlẹ̀ Kogi àti Cross River –Osagie Àwámárídìí ni iṣẹ́ Elédùwà, ṣùgbọ́n ọmọ èèyàn lọ́pọ̀ ìgbà má a ń fẹ́ tú fín ìn ìdí i kóòkò láti mọ kín gán án ní ń gbénú-un rédíò fọhùn. Bí ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ènìyàn 148 míràn lárùn Covid-19 ní Nàìjíríà–Àjọ NCDC
Ènìyàn 148 míràn lárùn Covid-19 ní Nàìjíríà–Àjọ NCDC Ó ti pé ẹgbẹ̀rún mẹ́ta àti márùndínládọ́jọ èèyan tó ti ní àrùn apinni léèmí yìí ní Nàìjíríà. Ìpínlẹ̀ Èkó ló ṣì ń léwájú.Ní bí a ṣe ń kó ìròyìn yìí jọ. Iye ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ẹ wọ ìbòmú tàbí kí ẹ rugi oyin – Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá
Ẹ wọ ìbòmú tàbí kí ẹ rugi oyin – Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Ọlọ́pàá èwo n tèpè ni àṣà tó gbayé kan tẹ́lẹ̀ , ṣùgbọ́n ní àsìkò kòró yìí, ó dà bí ẹni pé wọ́n ti sún ilé iṣẹ́ ọ̀hún kan ògiri ...
Read More »chucks Comments Off on Nollywood: A post from Bala Dihis..
While others are using their movies to showcase their military might, intelligence, rich culture, wild sense of imaginations, futuristic ideas, rich history, government propaganda and cultural supremacy. Nollywood is busy showing Nigerians that killing people and sacrificing their body parts ...
Read More »ayangalu Comments Off on Candomble: Pure truth without any form of sugarcoating!
What is Candomble?Between the 16th to 19th centuries, West and Central African descents, the majority of them from Yoruba, Bantu, and Fon ethnic groups were transported to Brazil during the Atlantic slave trade. Each of these ethnic groups carried along ...
Read More »Ilé tútùỌ̀nà tútùTútù tútù là n bá ilé OluweriA dia fún Oluweri mogboojoÀtòjò AteerunIlé Oluweri kìí gbónáIlé òní gbóná mó wa Àṣẹ Ire O! Peaceful housePeaceful lifeIn peace we meet the house of OluweriIt was divined for Oluweri mogboojoCome rain ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more