Iléeṣẹ́ Ààrẹ ló sọ pé Ìròyìn tó ń jà rànyìnrànyìn kiri pé Ààrẹ Muhammadu Buhari tí darí jin arábìnrin náà kìí ṣe òtítọ́ rárá.Ki àwọn èèyàn kọtí ọ̀gbọin sí i.Ní oṣù kínní ọdún yìí ni ilé ẹjọ́ dá arábìnrin Maryam ...
Read More »
ayangalu Comments Off on Maryam Sanda ṣì wà lẹ́wọ̀n, Buhari kò dáa sílẹ̀.
Iléeṣẹ́ Ààrẹ ló sọ pé Ìròyìn tó ń jà rànyìnrànyìn kiri pé Ààrẹ Muhammadu Buhari tí darí jin arábìnrin náà kìí ṣe òtítọ́ rárá.Ki àwọn èèyàn kọtí ọ̀gbọin sí i.Ní oṣù kínní ọdún yìí ni ilé ẹjọ́ dá arábìnrin Maryam ...
Read More »ayangalu Comments Off on Èmi kò ní àrùn coronavirus – Yahaya Bello
Gomina ipinle Kogi,Ogbeni Yahaya Bollo lo n forere lori ero ayelujara pe ki won se fi orokoro ko oun lorun, oun lo ni arun covid-19 gege bi awon oloselu Kan se n gbee kiri. O ni loooto ni adari aabo ...
Read More »Aiba won si nibe ni aiba won da sii. Eyi lo mu ki Alaga ile-iwe ati oludari, Mama Winfrey Awoshika ati Ibironke Adeyemi pese iresi, ewa, gaari ati ororo repete fun awon ti o ku die fun ni awujo.
Read More »ayangalu Comments Off on Àkó̩kó̩ Technical University Ibadan pèsè aso̩ ìbomú àrà ò̩tun fún ìpínlè̩ Oyo
Àkó̩kó̩ Technical University Ibadan pèsè aso̩ ìbomú àrà ò̩tun fún ìpínlè̩ OyoÌròyìn láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí Akoko Technical University to fi ikale si ilu Ibadan se bebe ni irole ana. Won pese aso ibomu ara otun fun ijoba ipinle Oyo. ...
Read More »ayangalu Comments Off on Happy Ose Ifa to all Ifa devotees globally.
Happy Ose Ifa. An Odu references all situations, circumstances, actions and consequences in life, based on the innumerable ese (poetic tutorials/recitations) relative to the 256 Odu coding. In other words an Odu is your life path. Each Odu has over ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ìjìyà ‘Frog Jump’ ni ọlọpàá India fi jẹ àwọn tí kò bọwọ fún òfin kónílé-o-gbélé
Ìjìyà ‘Frog Jump’ ni ọlọpàá India fi jẹ àwọn tí kò bọwọ fún òfin kónílé-o-gbélé Fẹ́mi Akínṣọlá Oríṣìríṣi ìjìyà ni ìjọba orílẹ̀-èdè India ti gbà nípaṣẹ̀ àwọn agbófinró láti máa jẹ àwọn kọ̀lọ̀rànsí tí kò bọ̀wọ̀ fún òfin kónílé-ó-gbélé ní ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àdúrà làsìkò yí gbà pẹ̀lú ìfaradà láti ṣẹ́gun àrùn apinni léèmí Coronavirus–Ààrẹ Buhari
Ààrẹ Buhari kí àwọn ọmọ Nàìjíríà kú àfaradà bí gbogbo nǹkan ṣe ń lọ lásìkò Coronavirus yìí Nínú ọ̀rọ̀ ìkínni kú ọdún Àjíǹde tó fi ṣọwọ́ sáwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ààrẹ Buhari ṣàlàyé pé ìgbáyégbádùn àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kìí ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àwọn dókítà ilẹ̀ China tó wá sí Nàìjíríà kò ní tọ́jú aláìsàn kankan’
Àwọn Dókítà láti ilẹ̀ China tó ṣẹ̀sẹ̀ dé sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nítorí àjàkálẹ̀ àrùn Coronavirus kò ní tọ́jú aláìsàn kankan. Iléeṣẹ́ láti ilẹ̀ China to tó ṣe ojú ọ̀nà àti ojú irin( CCECC Nigeria), ló fi àtẹjáde náà léde pé ...
Read More »Minisita fun eto iroyin ati asa ni orileede yii, Alhaji Lai Mohammed ni ijoba apapo ko ni gba ki awon kan fi iroyin aboosi da ilu ru. O ni “oloju ko ni laju re sile ki talubo woo”. O ni ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ẹlẹ́wọ̀n 2600 ni ìjọba tú sílẹ̀ ní Nàìjíríà nítorí àrùn apinni léèmí Coronavirus
Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti tú ẹlẹ́wọ́n tó lé ní ẹgbẹ̀rún méjì sílẹ̀ ní ọgbà ẹ̀wọ̀n káàkiri orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Aregbesọla ní Ìjọba gbé ìgbésẹ̀ náà láti dẹ́kun ìtànkálẹ̀ àrùn Coronavirus ní Nàìjíríà. Mínísítà fún ọ̀rọ̀ abẹ́lé lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà náà ni àwọn ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more