Ṣé Yorùbá bọ̀ wọ́n ní báyé bá tojú àgbà bàjẹ́, àìmọ̀wàáhù wọn ní. Èyí ló díá fún bí àwọn tọ́rọ̀ kàn lágboolé òṣèré e tíátà se ń lọgun tantan pé,láyé ọjọ́sí, eré ìtàgé jẹ́ gbajúgbajà láwùjọ àwọn onítíátà lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. ...
Read More »
ayangalu Comments Off on Peter Fatomilola ní àìsí ẹ̀kọ́ ń mú káwọn òṣèré tíátà ó máá ṣe oun tí kò tọ́
Ṣé Yorùbá bọ̀ wọ́n ní báyé bá tojú àgbà bàjẹ́, àìmọ̀wàáhù wọn ní. Èyí ló díá fún bí àwọn tọ́rọ̀ kàn lágboolé òṣèré e tíátà se ń lọgun tantan pé,láyé ọjọ́sí, eré ìtàgé jẹ́ gbajúgbajà láwùjọ àwọn onítíátà lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ọ̀nà Jìbìtì 2
Ọ̀nà Jìbìtì 2Awon miiran maa n duro si opopona bi eni ti moto won baje. Won le mu omo ileewe kan tabi meji si egbe won gege bi eni to nilo iranlowo. Awon to ba duro ti won ti ko ...
Read More »ayangalu Comments Off on Buhari bá ìpínlè̩ Eko ké̩dùn
Buhari bá ìpínlè̩ Eko ké̩dùn – Ìròyìn lati o̩wó̩ Yínká Àlàbí Ojo buruku esu gbomi mu ni ojo isinmi oni je fun awon ara agbegbe Amuwo Odofin ni adugbo FESTAC.Ijamba ina naa bere ni aago mesan-an aaro. Opa epo ni ...
Read More »ayangalu Comments Off on Nítorí Àrùn Coronavirus Ìjọba Àpapọ̀ Ní Káwọn Arìnrìnàjò Láti Orílẹ̀èdè Amẹ́ríkà, Gẹ̀ẹ́sì, Faransé Àtorilẹ̀èdè Mọ́kànlá Míràn O Gbélé Wọn
Bákan náà ni Ìjọba àpapọ̀ tún ṣàlàyé pé àṣẹ yìí ló bẹ̀rẹ̀ sí ní fi ẹsẹ̀ múlẹ̀, bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ Sátidé, ọjọ́ kọkànlélọ́gún oṣù kẹta ọdún 2020.
Read More »ayangalu Comments Off on Ikú agbábó̩ò̩lù: LMC fa ìbínú yo̩
Ikú agbábó̩ò̩lù: LMC fa ìbínú yo̩– Iroyin lati Owo Akinwale Taophic. Latari iku odo agbaboolu, Chineme Martin’s, eni ti o pade iku ojiji ni abala akoko ifigagbaga ose ketalelogun liigi orileede wa Nigeria, NPFL, ti o waye laarin Nasarawa United ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn wọ́gilé ìyọnípò Oshiomole gẹ́gẹ́ bíi alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC
Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn wọ́gilé ìyọnípò Oshiomole gẹ́gẹ́ bíi alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC
Read More »ayangalu Comments Off on Alárùn kòkòrò corona e̩lé̩è̩ké̩ta fara hàn
Arabinrin ti o sese ti ilu London de ni o bere si nii wuko ti o si n se kata. Ni eyi ti o mu ki o fara re sile fun ayewo coronavirus.
Read More »ayangalu Comments Off on Ọ̀nà Jìbìtì
Bi ara ipede Radio Naigeria O.Y.O ni aye atijo, won ni, “Ifunra loogun agba, pasa ko funra, o ja sina, aja ko funra, aja jin, ti onile naa ko ba funra, ole ni yoo ko lo”. Eyi ni o difa fun gbogbo awa ti a maa n gbe moto lo si ibi inawo.
Read More »ayangalu Comments Off on Ìwà Pẹ̀lẹ́ (Good Character)
Ìwà Pẹ̀lẹ́(Good Character) is ultimately the basis of moral conduct in Yorùbá Culture and a core defining attribute of an Ọmọlúwàbí. Also, One of the basic concepts of Indigenous Tradition, as the welfare and development in life.
Read More »ayangalu Comments Off on Àríwá Nàìjíríà, Ẹ Sọ Ẹran Jọ̀bọ̀jọ̀bọ̀ Nù Bí Ẹ Ṣe Yọ Sanusi – Soyinka
Ọ̀jọ̀gbọ́n Wọlé Soyinka ti bu ẹnu àtẹ́ lu bí Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano, lábẹ́ ìsàkóso Gómìnà Abdullahi Umar Ganduje, lórí bó ṣe rọ Lamido Sanusi lóyè, gẹ́gẹ́ bí Emir ìlú Kano.
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more