OAU se ìràntí àwon akoni tí won pàdánù èmí won sí owó àwon omo egbé òkúnkùn ní ogún odún séyìn. Àwon alámòójútó àti akékòó ilé-èkó gíga Obafemi Awolowo University ti ilé- ife, máa péjo sí gbàgede Amphitheater tí ilé èkó ...
Read More »Ifa/Orisa books
Ifa/Orisa books at affordable prices (still in stock) Order for yours now!!!! 1. Ifa: Ohun Enu Olodumare Ifa: God’s Sacred Message to Mankind 2. Ifa: Ohun Ijinle Aye Ifa: Philosophy of Life 3. Egbe: The sacred tie that binds 4. ...
Read More »Oríkì Òrìsà
Oríkì Òrìsà is very important in Yoruba. It is the Oríkì that enables us to understand the characteristics and ways of Òrìsà. Iyalorisa Omitonade Ifawemimo
Read More »Iwure Toni: Orí Ma Jẹ Kí Ire Tí Moní Kó Pẹ̀dí ..
Ifá ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díOrí ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díOlú ọ̀run ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díNítorí ata wẹẹrẹ kín pẹ̀ dí nínú ọbẹ̀ ata wẹẹrẹ Mo sé ní iwure fún ...
Read More »Èèmò lukutu pébé.
Òdókùnrín tí ó n fi èro ayélujára gbáni, tí ó n se Yahoo yahoo, ni owó ti tè níbi tí ó ti n gbé òkú arábìnrin tí ó pa sí hòtélì lo. Owó sìkún àwon agbófinró ti te odókùnrin tí ...
Read More »Egbé agbá bóòlú fún orílè èdè Nìjíríà àti ti Cameroon: Ìghàló gégé bíi òdómokùnrin tí ó gbégbá orókè nínú eré bóòlù náà.
Egbé agbá bóòlú fún orílè èdè Nìjíríà àti ti Cameroon: Ìghàló gégé bíi òdómokùnrin tí ó gbégbá orókè nínú eré bóòlù náà. Omo egbé agbá bóòlù fún orílè èdè Nìjíríà tí na àwon omo egbé agbá bóòlú Cameroon ní méta ...
Read More »Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó.
Arewà obìnrin kan ni ó gbé o n je omo (oyàn) rè han nínú àwòrán òun àti oko àfésónà kí won tó se ìgbéyàwó. Arábìnrin tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà ní ó fi orí oyàn hàn níbi àwòrán ...
Read More »Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won.
Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won. Àwon arewà omodé méjì yí, ni won ti kí a mo rírì ìfé tí èjè máa ni sí ara won. Omokùnrin kan láti orílè ...
Read More »Ifa-lafinimona: Ifa, the Pathfinder.
Ifalafinimona Ifa is the pathfinder embrace it as you would your belover.
Read More »Iba Eleiye
Orunmila wi Awo tan.Ifa mi Awo ku mi Bara Agbonmiregun.Ifa ni nibo ni Awo ku si?Mo ni o ku awon Ajagaruwa.Mo ni o ku awon Alsgbede orun ko mero ileke.Mo ni o ku Okoko sii wele. Ifa lo di obiri Mo ni ...
Read More »