Òdókùnrín tí ó n fi èro ayélujára gbáni, tí ó n se Yahoo yahoo, ni owó ti tè níbi tí ó ti n gbé òkú arábìnrin tí ó pa sí hòtélì lo. Owó sìkún àwon agbófinró ti te odókùnrin tí ...
Read More »Egbé agbá bóòlú fún orílè èdè Nìjíríà àti ti Cameroon: Ìghàló gégé bíi òdómokùnrin tí ó gbégbá orókè nínú eré bóòlù náà.
Egbé agbá bóòlú fún orílè èdè Nìjíríà àti ti Cameroon: Ìghàló gégé bíi òdómokùnrin tí ó gbégbá orókè nínú eré bóòlù náà. Omo egbé agbá bóòlù fún orílè èdè Nìjíríà tí na àwon omo egbé agbá bóòlú Cameroon ní méta ...
Read More »Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó.
Arewà obìnrin kan ni ó gbé o n je omo (oyàn) rè han nínú àwòrán òun àti oko àfésónà kí won tó se ìgbéyàwó. Arábìnrin tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà ní ó fi orí oyàn hàn níbi àwòrán ...
Read More »Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won.
Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won. Àwon arewà omodé méjì yí, ni won ti kí a mo rírì ìfé tí èjè máa ni sí ara won. Omokùnrin kan láti orílè ...
Read More »Ifa-lafinimona: Ifa, the Pathfinder.
Ifalafinimona Ifa is the pathfinder embrace it as you would your belover.
Read More »Iba Eleiye
Orunmila wi Awo tan.Ifa mi Awo ku mi Bara Agbonmiregun.Ifa ni nibo ni Awo ku si?Mo ni o ku awon Ajagaruwa.Mo ni o ku awon Alsgbede orun ko mero ileke.Mo ni o ku Okoko sii wele. Ifa lo di obiri Mo ni ...
Read More »The Ogun Festival In Omupo, Kwara State, Nigeria – Photos
Bellow is the photo of Elemoso Ogun of Ijagbo Land and Oluode Aluwo Of Offa at the Ogun Festival In Omupo, Kwara State, Nigeria. See another photo bellow
Read More »Annual Ifa Festival: Save the date!
Please sing along with me as follows:- Mi o fi sawada mo wi o, mi o fi sawada Bi mo t’ayewa onifa ni N o seMi o fi sawada mo wi o This is not a joke, I declare, I am ...
Read More »Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe.
Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe. Owó sìnkú àwon agbófinró ti orílè èdè Nìjíríà ti te Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe ní ònà gbòòrò. Nígbà tí ó ní irú opolo láti se èyí, kílódé tí ...
Read More »Ogbè Até
Owó òtún mi ni mo fi n gba ire Adífáfún Sará Sará N’ílé olódùmarè la gbé n báwon Lóri orí eni òré òhun tìmùtìmù rere Àtélewó mi òsì Ni mo fi n gba ìfà Adífáfún Sèbí Sèbí N’ílé olódùmare ni ...
Read More »