Ọya is one of the very powerful African Goddesses (Orisa). A Warrior-Queen, she is the sister-wife of the God Sango, to whom she gave the energy to produce storms. A lot of Ọya’s power is rooted in the natural world; ...
Read More »Bí ewúrẹ́ bá bojú wo ẹ̀yìn
Á fi èpè fún elépè Mo sé ní ìwúre wípé gbogbo ọ̀tá tí o bá ń robi tàbí sebi sí èmi àti ẹ̀yin lẹ́yìn yoo ma fí orí ara wọn gbe láṣẹ Ọlọ́run Olódùmarè Àsẹ Eu oro para que qualquer inimigo ...
Read More »Ọmọ: Ẹ̀bùn Edùmarè !
Ẹ̀bùn Edùmarè ni ọmọ Ẹ̀rí ìfẹ́ rẹ̀ sí wa ni wọ́n Èdùmàrè à ń bẹ̀ ọ́ Bá wa wo àwọn èwe yè Fi wọ́n fún àwọn tí ń wojú rẹ fún ẹ̀bùn wọn Má ṣe jẹ́ kí wọ́n kú mọ́ ...
Read More »The Fact That Adó Ewi Is The Home Of Òrúnmìlà Is Undisputable.
Although, we all known that Ile-Ife is the cradle of all Yoruba race, and it is a sacred town that all the deities descended to, so any orisa can be celebrated there, but when they lived many years in otu Ifè,
Read More »Pari Owe Yii
Ohun to wa leyin Ofa!
Read More »What Odu Ifa says in Osa logbe
Today, Sunday, Ojo Aiku (day of immortality), Ose Ifa, looking at the Odu, “Osa logbe”, what else can we request from Ifa if not longevity because he/she who is endowed with longevity receives goodness Just listen to one of the stanzas:- ...
Read More »2019 World Ifa/Orisa Pilgrimage In Ekiti And Ife.
I am very certain that Orunmila and other Orisa will be dancing and enjoying with what is happening with Ifa and Orisa Practitioners Community presently. Why? Because, miraculously with their sanctions, we have promoted the brotherhood among the Orisa and ...
Read More »Asiri àwo kintú,
Asiri ẹ̀tú kintú, Iwọ iwori bógbè IFA, Ki owá bo asiri mi, Iwọ iwori bógbè. Mogbá ládùrá wipè loni ọjọ àbámẹtá asiri gbógbó wa koni tu kotobó lailai,gbogbo abá ti aba da loni yio jẹ mimusẹ, Aṣẹ̀ aṣẹ̀ aṣẹ̀. Aṣẹ̀ aṣẹ̀ aṣẹ̀.
Read More »Orí ejò
Bí kò bá sí ọpẹ́lọpẹ́ orí, à bá tí mú ejò digi lókoÌtàkùn mà lejòKíni yoo bá ejò ṣẹ́gun Orí ejò ní yoo bá ejò ṣẹ́gun Orí ejò Mo sé ní ìwúre pe orí kálukú wa yoo báwa ṣẹ́gun ọ̀tá gbogboAkò ní ...
Read More »European Ancestor Versus Oodua Ancestor: Which One Marches Your DNA?
OODUA Ancestors are well over 50,000years old in existence; While European Ancestors conscripted by the Roman Vatican are not more that 5,000years old in existence. According to Archeological research reports. How can a reasonable human being abandoned honouring his Ancestor ...
Read More »