E fu’n Foto yii ni Oruko
E daku’n e be wa fu’n foto yii ni Oruko ka’n to dara!
Read More »A ku ojumo oooooooo!
Oba to silekun ojo oni, yoo sina ayo fun wa, yoo sina aje fun wa, A ko no seru egbe wa, ire ayo wa ko ni fo wa ru(Ase). #AKARA_IMORAN : Ma se gbo oro okere, gbiyanju lati wadi ohun ...
Read More »Gbiyanju lati toju obi i re !
Ojumo to mo wa lonii, ojumo ibukun, ojumo igbega, ojumo aseyori, ojumo ire, ojumo itunu, ojumo ayo, ojumo idunnu ni yoo je fun gbogbo wa lase Edumare(Ase). # AKARA IMORAN : Gbiyanju lati toju obi i re, niwon igba ti obi ...
Read More »Happy Yoruba New Year.
Many people do not know that Yoruba operates with a four day calendar week. 28 days in one month. Meanwhile Aiku, aje, isegun, ojoru, ojo’bo, eti, abameta were later inventions. We have each day of the week assigned to each ...
Read More »Llegando a oke igeti home de Orunmila.
Foto kerediti –
Read More »Obara Oturupon/Obara Tiele Corpus by Ifa Chief Priest
Good morning my people, how was your night? Hope it was enjoyed. I wish you all happy new month, may this month bring us everlasting joy and happiness amen. It is OBARA OTURUPON/ OBARA TIELE corpus that revealed this morning, ...
Read More »Mohammed Ali joins his ancestors.. Sun re o !
The great Mohammed Ali bids the Yoruba race a Happy New Year as he joins his ancestors! May he be warmly received! Aase!
Read More »Idajo mi ree…
Leyin gbogbo atotonu awon agbejoro mejeji ati iwadi to peye, ariipe ojebi esun ti a fikan e, nitori na idajo mi ree, ile ejo yi so e sinu: i) igbega; ii) aseyori; iii) idunnu; iv) ayo; v) ire owo; vi) ...
Read More »Obara Irete
I I I II II II I II ObaraIrete Ponusesere Awo Ile Agbonniregun O difa fun Agbonniregun Oloja Oribojo Nijo ti won ji Ti won n foribale fun Ikin won Eni ba foribale a jogbo Eni ba foribale a jato ...
Read More »