Ààre Buhari lo rí àwon omo egbé CAN ní ilé ìgbìmò ní ìlú Abuja.
Ààre Muhammadu Buhari ti lo rí àwon omo egbé Christian Association of Nigeria (CAN ) ní ilé ìgbìmò ní ìlú Abuja.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ààre Buhari lo rí àwon omo egbé CAN ní ilé ìgbìmò ní ìlú Abuja.
Ààre Muhammadu Buhari ti lo rí àwon omo egbé Christian Association of Nigeria (CAN ) ní ilé ìgbìmò ní ìlú Abuja.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on À n yan Àntà ( alligator ) tí a pa nínú oko ìresì wa.
Ìsinmi tòtè yí mà yàtà gan o, ó ti è ti dùn jù …járá oko yí mà da gan ni oo . Àwòrán obè aláta yéríyérí n bò láìpé.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Òdóbìnrin ni ó ya àwòrán orúko Runtown gangan sí ìdí rè.
Níbáyìí, ojú wo ni òrékùnrin rè ma fi wò ó tí ó bá rí ìdí òdóbìnrin yí?. Àwòrán tí ó ti gba èro ayélujára kan ni ti obìnrin tí ó ko orúko Runtown gangan sí ìdí rè. Olórin ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on E wo ejò tí aládùúgbò mi pa, e jò wó kíni orúko rè.
Aládùúgbò mi ló pa ejò nlá yí ní kùtùkùtù òwúrò àná … Oúnje ti se.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Laura Ikeji Kanu tún yo ní àrà òtò.
Onísòwò aso àti olù gbé eré jáde, Laura Ikeji gbé lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán tí ó ya ni lénu yí.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán ayeye ìsìnkú Obi Madubogwu.
Akoni òsèré , Obi Madubogwu tí ó kú ní ojó kejìdínló’gbòn osù kejo ( 28/8) nígbà tí ó jèrora ìtò súgà fún bí odún díè séyìn ni won ti sin sí ìlú rè ní Ogidi ìpínlè Anambra. Gbajúgbajà òsèré ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ajé omo Olókun.
Òrìsà ni olókun jé, a gbó wípé òun ni ó bí ajé, ó tún jé òrìsà orò àti ti ìsàlè òkun. Olókun ni ó n darí omi ó sì ní àse l’órí gbogbo ìsèdá inú omi . Olókun máa ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Nnamdi Mpiti tí ó jé akunjú (make up artist) pín àwòrán yí .
E má jé kí èrù bà wá . Kíkùn lásán ni , àti wípé èjè iró ni ó wà níbè “.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán tí Tonto Dikeh àti Halima Abubakar yà tí won sì rewà nínú àwòrán náà.
Òsèrè orí ìtàgé, Tonto Dikeh gbe lo sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán tí ó rewà yí tí òun àti òré rè tímótímó , òsèré Halima Abubakar yà.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán bàbá àti àwon omo rè obìnrin méfà.
Àwòrán bàbá kan láti orílè èdè Nàíjíríà pèlú àwon omo rè obìnrin méfà tí ó rewà. Baba tí orí rè wú pín àwòrán àwon omo rè obìnrin méfà. Won rewà gan ni. Nse ni ó dàbi kí èmi náà ...
Read More »