Home / Art / Àṣà Oòduà / Mooko-mooka: Akoto ede Yoruba
Yoruba Festival

Mooko-mooka: Akoto ede Yoruba

Mooko-mooka: Akoto ede Yoruba

Ni abala mooko-mooka ose yii, akoto ede Yoruba ni a maa gbe yewo. Akoto je ona ti n gba ko ede Yoruba sile laye ode-oni. Eleyii to yato si ti aye atijo.

 

Aye Atijo Aye ode-oni
1 Ase Ase O
2 Agbagba Agbaagba
3 Agbelebu Agbelebuu
4 Agbowode Agbowoode/ Agbowo-ode
5 Aisedede Aisedeede
6 Aiyekoto Ayekooto
7 Ake Aake
8 Alabaro Alabaaro
9 Aladugbo Aladuugbo
10 Aladura Aladuura

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti