Previous Military Head of State, Ibrahim Babangida with one of his girls, Halimatu in 1991. Halimatu is the last daughter of late Maryam Babangida.
Aheso oro ni iku BabangidaYinka AlabiAriwo iku ajagunfehinti to o tun je Aare Ologun ni orileede yii tele ri, Ibrahim Babangida ni o gbode Kan.Ariwo yii po lori ero ayelujara lati idaji oni sugbon Ogbeni Kazim Afegbua ni iro ni. O ni koko ti ara ota n le ni ara oga oun le. O ni loooto ni ara ti di ara agba fun Babangida sugbon eni ti Olorun ko pa, ko le ku.Olowo otun Babangida ro awon eniyan ki ma ...