Home / Naija Gist / Religion / Awure Ifa idabobo fun OMO eni lowo iku:
What Is Ifa

Awure Ifa idabobo fun OMO eni lowo iku:

Isu ni ti inu pon

Ogede pon adun de eyin
Adifa fun Oyeku tii nse omo eleyin Ogbe
Omo eni ni wo ile de ni.
Nje iku dakun mapa Oyeku tii nse omo eleyin Ogbe.
Nitori omo eni ni wo ile de ni.
*Iku dakun mapa omo mi (Goriola,Niyi ,et)
Nitoripe omo eni ni wo ile de ni.

Lilo:Ete Oyekulogbe sori iyerosun ,ke wa ma pe ohun IFA yii si ,a tun ma pe oruko omo yin si.Levin eyi abu si omi iwe atu bu die si omi mumu.Lagbara Eledumare eleyin ko ni siwaju ,ani fi owo gbe omo wa sin o!!Ase

Given to me by my adopted boy aged 12,who is a baba alawo.-(Ifatunmibi)

~~Alebiosu Goriola

About admin

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

ifagrithm

Ifagrithm: The Mathematics In Ifa (The Yoruba Divination System)