Home / Naija Gist / Religion / Iwure Owuro 28.05.2016
Egungun

Iwure Owuro 28.05.2016

E MAA WI TELE MI :
…………
*Edumare fi aanu re wa mi ri.
*Oluwa s’ekun mi d’erin.
……
*Edumare koni fi omo pa mi lekun
*Ododo/Omo mi ko ni re danu.
*Emi ko ni di arisa fun omo mi.
*Omo mi ko ni di arisa fun mi.
*Ounje omo ko ni koro lenu mi.
*Edumare ko ni fi mi pa obi mi lekun(ASE).

 

IWURE OWURO 27/05/2016
……………………………………………………………….
E MAA WI TELE MI :
……
*Orile-ede yii ko ni le mo mi.
*Nigeria ko ni baje.
*Emi maa gbe ori ile yii se rere.
*Wahala mi ko ni ja s’asan.
*Won ko ni toro iku fun mi.
*Eledumare dakun so yeye mi di ayeye(ASE).

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti