Home / Art / Àṣà Oòduà / A kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* ?? lónìí ooo.
Nigeria Flag

A kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* ?? lónìí ooo.

A kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* ?? lónìí ooo. Èmí wa yóò se púpò rè láyé.
E jòwó, e má sì gbàgbé láti se *ìwúre* fún orílè èdè *Nàìjíríà* ?? nítorí wí pé *”Ìròrùn igi ni ìròrùn eye”*. Àgbájo owó la fi ñ sòyà, àjèjé owó kan kò gbérù dórí.

A sì tún kú àmójúbà *osù Òwàwà (October) tuntun*. Osù aláyò ni yóò jé fún wa láse Èdùmàrè. Èmi ò ní dòkú, èyin náà ò ní dòkú, gbogbo wa ni a yóò rí òpin odún yìí láyò àti àlááfíà… *(Ase! )*
????????
*omo oòduà rere ń kì I yín…

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti