Home / Art / Àṣà Oòduà / Agbajopo Ibinu da ija Eneya-meya si le, Eyi ti o mu emi Omokurin ka lo ni ilu ‘India’.
india

Agbajopo Ibinu da ija Eneya-meya si le, Eyi ti o mu emi Omokurin ka lo ni ilu ‘India’.

Ogogorun awon olugbe ti ẹya Indian ilu ibi ti Ọdọkùnrin ti kú, eyi ti won fura si wipe olo aloju oògùn, eyi ti o si
fa rogbodiyan larin awon ati awon omo orilende ti ile Afirika eyin won un se atipo ni mile na, arigbo wipe aga irin ijoko lati kolu
ni awon ijanduku na lo lati ba awon tonraoja ni ile itaja kan ni agbegbe ja.
Ija na besile ni ojo aje leyin ago olopa ni agbegbe kan ti won pe ni ” Greater Noida, ni satelaiti ilu ni New Delhi” tu marun sile lara awon omo Afika ti won lo si ile iwe eko giga ni orile ede na nipa ti odomokurin ti oku na, ni pa pe awon agbofin ro na so wipe won ko ni eri ti o lodi si won.

Ati wipe ile ise telifisionu kan se afihan bi agbejopo awon ijanduku na se kolu oko ayokele kan pelu igi, nigba ti awon miran si lo irin ijoko lati lu awon tonraoja ni ile itaja  awon olopa tun salaye wipe awon mawa ni o fi ara gbogbe, lara awon omo Afirika ti won ka we ni orile ede na, ati wipe minisita fun awon ti o se atipo ni ile ajeji, so wipe awon alase ma se iwadi oun ti o se okun fa isele na.
Ati wipe awon Afirika ti won gbe ni ileede na so wipe, ni gbogboigba ni won ma un koju iyasoto, ati wipe won ju oro na
si gbagede oro neyi iku omo orile-ede ilu congo lori ikorira ija ti awon ara ilu india na un ba won ja si ni odun ti
okoja.

 

Lehin eyi, iko ti Afirika ni orile-ede na ni ilu New Deihi, fun awon akekoo ni imoran lati yago fun ile-iwe ni olu ilu na fun abo emi arawon.  Olopa mu marun lara awon omo ile Nigaria, ni eyi ti o se okun fa wipe awon omo nigeria ti won gbe ni orile-ede na
lo lati fi eronu han wipe won pe ikan ninu won, leyin ireyin awon olopa na ni lati fi won sile lala gba kobo lowo won,
nipa se wipe won ko ri esun kankan ka si won lowo.

 

Olori akeke ni orile-ede na, eyi ti oruko re unje Samueli Jack, so wipe isele rogbodiyan Ojo aje na, je o kan titun ni
apẹẹrẹ ni kikorira eda omo enikeji iwa-ipa si Afirika. O tun te si waju wipe won korira won ni pa awo awon omo orile-ede
alawo dudu.

 

English Version

Continue after the Page Break

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

world

Russia Ukraine War: US Drones Attack Russia | Macron’s Hypocrisy Exposed | Vantage with Palki Sharma