Ogbontarigi agbaboolu omo Naijiria, Ahmed Musa, ti n le waju bayii ninu awon agbaboolu to rawon julo niluu Russia. Iroyin yii jade ni kete ti egbe agbaboolu re, CSKA Moscow jawe olubori nigba ti won pade pelu Dynamo pelu ayo meji sodo. Musa naa gba goolu kan wole ninu ifesewonse to waye lopin ose yii eleyii to mu apapo boolu to gba wole je mefa ninu liigi oreede Russia.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more


