Home / Art / Àṣà Oòduà / Akékòó bìnrin méjì ja ìjàgbara látàrí òrékùnrin ní ilé-èkó gíga ifáfitì tí a mò sí Tai solarin University of Education, ní ìpínlè Ogun.

Akékòó bìnrin méjì ja ìjàgbara látàrí òrékùnrin ní ilé-èkó gíga ifáfitì tí a mò sí Tai solarin University of Education, ní ìpínlè Ogun.

Fídíò àti àwòrán àwon òdóbìnrin méjì tí ó ñ jà látàrí òrékúnrin kan ni ó ti gbalè kan .
Akékòó ni àwon arábìnrin méjì yí àti wípé akékòó ilé-èkó ifáfitì ti Tai Solarin University Of Education ni won, ìpínlè Ogun, won fi èsùn kàn wípé ìjà won dá lórí arákùnrin tí ó ñ se yáhoo yahoo tí àwon méjèjì jo ñ fé.

Gégé bí ìtàn se so, ní ilé ìgbé àwon Akékòó tí a mò sí Hostel ni èyí ti selè, ní ibi tí kò jìnà sí mósálásì Ijele.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti