Home / Art / Àṣà Oòduà / Akékòó ilé-èkó gíga tí a mò sí Polytechnic ti ìlú Ede ní ìpínlè Osun ni àwon ará ìlú ti lù pa .

Akékòó ilé-èkó gíga tí a mò sí Polytechnic ti ìlú Ede ní ìpínlè Osun ni àwon ará ìlú ti lù pa .

Ní àná ni akékòó ilé-èkó ti poly Ede fi okò pa ènìyàn bíi márùn-ún tí àwon omo tí ó sèsè fé wo ilé-èkó náà pélù okò rè.
Bí ó tilè jé wípé, àwon ojú tí ó wà níbè náà so wípé ñse ni omokùnrin náà ti mu otí àmupara tí ó sì ti lo àwon òògún olóró míràn tí won rí nínú okò rè. A ri gbó wípé orúko olóògbé náà a máa jé Fisayo.
Akékòó yí jé Akékòó parí ní eka-èkó Building Technology ti ìlú Ede ní ìpínlè Ede nígbà tí won fi Òkadà wá Fisayo lo tí owó sì bàá tí won sì nàá pa tí àwon òré rè sí mórí bó ní tiwon.
Àì fi arabalè wakò ló sekú pa olóògbé yìí, ìkìlò ti wà wípé kí á mutí tí a bá fé wa okò.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti