Home / Art / Àṣà Oòduà / Annie Idibia da padà fún olùtèlé rè tí ó pè é ní omobìnrin tó “wor wor “.
Annie Idibia

Annie Idibia da padà fún olùtèlé rè tí ó pè é ní omobìnrin tó “wor wor “.

Annie Idibia fi àwòrán yí sí orí èro ayélujàra rè (instagram) tí ó rò wípé kò rewà  pè é ní omobìnrin tó ” wor wor ” .
Ìyá omo méji tí òhun náà sì da padà fun pé :bí ìyá rè….

Continue after the page break for English Version

About ayangalu

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

policeman

Ọ̀gbẹ́ni Olaoye déèdé pòórá nílé ìtura kan nílùú Akure

Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...