Home / Art / Àṣà Oòduà / Arábìnrin omo odún méèdógbòn, tí ó tún jé a fi ewà s’oge, Chidimma Leilani Aaron ti gba àmì èye gégé bíi omidan àkókó ní orílè èdè Nìjíríà tí odún 2018.

Arábìnrin omo odún méèdógbòn, tí ó tún jé a fi ewà s’oge, Chidimma Leilani Aaron ti gba àmì èye gégé bíi omidan àkókó ní orílè èdè Nìjíríà tí odún 2018.

,Chidimma Leilani Aaron, omo odún méèdógbòn láti ìpínlè Enugu ti tayo àwon métàdínlógún (17) tí won jo díje fún omidan àkókó ní orílè èdè Nìjíríà ti odún yí. O di eni kejìlélógójì tí yóò gba àmì èye yí ó sì lo ilé pèlú mílìònù méta náírà.
Ameh Rose ni ó se ipò keta tí Dunu sì se ipò kejì.
Gégé bí iwé ìròyìn daily times se se agbáterù rè, àjòdún tí ó máa n wáyé ní odoodún yí wáyé ní ilé ìtura ní ìlú Eko tí a mò sí Eko hotel. Òpòlopò àwon gbajúgbajà ènìyàn ni ô sì lo fún ojú lóúnje níbè.
Àwon Adájó ibè náà ni Rita Dominic, Ruchard Mofe Damijo, Olisa Adibua, Leesi Peter Vigbooro, Konye Nwabogor, Fade Ogbunro àti béè béè lo.
Ebuka àti Kayla Oniwo ni ó sì se agbáterù rè.

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

A list of prepared Yoruba numbers (Onka ede Yoruba 1 – 10,000)

A list of prepared Yoruba numbers (Onka ede Yoruba 1 – 10,000)

To understand the Yoruba language, common vocabulary is among the important sections. Common Vocabulary contains common words that individuals can use within daily life. Numbers are one section of common words found in daily life. If you’re interested to master Yoruba numbers, this post can help you to master all numbers in the Yoruba language using their pronunciation in English. Yoruba numbers are found in day-to-day life, so it’s essential to master Yoruba numbers. The below table provides the translation ...