Home / Art / Àṣà Oòduà / Arábìnrin yí ni ó wàású fún awakò yí, tí ó sì yi padà sí kìrìsìténì láti mùsúlùmí.

Arábìnrin yí ni ó wàású fún awakò yí, tí ó sì yi padà sí kìrìsìténì láti mùsúlùmí.

   Arábìnrin tí ó jé ò n lò èro ayárabíàsá (Twitter) tí a mo orúko rè sí Caramella Mou ní won fi èsùn kàn ní órí èro ayárabíàsá látàrí wípé ó wàású fún arákùnrin awakò kan tí ó jé mùsùlùmí ó sì yi padà sí kìrìsìténì.

Àwon kan takò ó wípé báwo ni ó se ma yí padà nígbà tí kìí se wípé kò ní èsùn télè.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti