Home / Art / Àṣà Oòduà / Asiwaju Sí Aso̩ Lójú Eégún “Operation Àmò̩té̩kùn” Láti O̩wò̩ Yínká Àlàbí
tinubu

Asiwaju Sí Aso̩ Lójú Eégún “Operation Àmò̩té̩kùn” Láti O̩wò̩ Yínká Àlàbí

“Asiwaju sí aso̩ lójú eégún “operation Àmò̩té̩kùn”
Láti o̩wò̩ Yínká Àlàbí

Asiwaju Bola Ahmmed Tinubu to je asiwaju agba ninu egbe oselu APC ni gbogbo aye ti n wa kiri lati ojo ti Abubakar Malami ti ni idasile Amotekun ko ba ofin mu.


Abubakar Malami ni olori eto idajo ni orileede yii. Gbogbo awon eniyan lo fe mo ibi ti Tinubu fi si lori oro Amotekun.

Awon kan ni Tinubu naa lo daa sile fun odun 2023. Awon kan ni Tinubu ko tile fara mo idasile re rara, won ni gbogbo nnkan ti owo Tinubu ba wa, ko si baba eni to le so pe ko ba ofin mu ni orileede yii.

Boya die lara awon awuyewuye yii naa lo ta si Asiwaju leti to fi da si oro naa.” Yoruba bo, won ki ” eti oba nile,eti oba loko,eniyan lo n je bee”.

Tinubu ni ko si ohun to lodi si idasile ajo idaabobo Amotekun. O ni eyi ko si salaye pe agbara ijoba apapo ko ka aabo ilu mo. O ni iranlowo ni Amotekun maa je fun awon ologun nitori pe ” alejo loju lasan ni,ko le rina to onile”.

Asiwaju gba awon gomina mefeefa niyanju lati lo se ipade pelu Malami, ki won je ki o mo idi idasile ajo naa. Ki won si se pelu Aare Mohammadu Buhari naa bo se ti wa nile

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Asiwaju Bola Ahmed Tinubu

Presidential Broadcast – President Tinubu chastised Fubara five times over the Rivers problem.

In accordance with Section 305 of the “1999 Constitution (The constitution, which we still operate, is Decree 24 and was promulgated into law by a military dictator General Abdusalam Abubakar, on May 5, 1999, and has become operative from May 29, 1999 till date), President Bola Tinubu has proclaimed a State of Emergency in Rivers State. After the situation in Rivers intensified to include pipeline vandalism and the bombing of the Transamadi pipeline, an emergency meeting with service chiefs and ...