Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwon ará ìlú dojú ìjà ko àwon Fúlàní ní Numan, Adamawa wón pa márùnlélógójì(45) tí won sì fi ogbé sì àwon tí ô kù l’ára .

Àwon ará ìlú dojú ìjà ko àwon Fúlàní ní Numan, Adamawa wón pa márùnlélógójì(45) tí won sì fi ogbé sì àwon tí ô kù l’ára .

Gégé bí Sani tí ó pin se so, àwon èèyàn Bachama ní alé àná ti dojú ìjà ko àwon fúlàní ní ilé tí won ngbé ní Kwadam Shafaran ìlú kéréje kan ní Numan ti ìpínlè Adamawa. Ó kéré jù márùnlélógójì (45) ni àwon fúlàní tí won pa tí òpò sì fi ara pa .
Òkú àwon tí ó kú ti wà ní Mósúárì tí ó wà ní Numan tí àwon tí ó fi ara pa sì wà ní ilé-ìwòsàn.

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Omisore

Àwàdà kẹrí-Kẹrì ni àwọn kọmití tó ní mi ò lè díje du ipò gómìnà APC ni 2026 n ṣe – Omisore

Yínká Àlàbí Awọn kọmiti to n ṣe àyẹ̀wò awọn oludije du ipo gomina labẹ ẹgbẹ́ oselu APC ti ja igbakeji gomina tẹlẹ ni ipinle Osun, Alagba Iyiola Omisore ati awọn mẹfa miiran.Wọn ni iwe wọn ko pe lati dije du ipo gomina ipinlẹ naa. Awọn mẹfẹẹfa to ku naa ni – Babatunde Oralusi, Oyedotun Babayemi, Dr. Akin Ogunbiyi, Benedict Alabi, Adegoke Rasheed Okiki, ati Senator Babajide Omoworare.Iyiola Omisore ni awada Kẹri-Kẹri ni awọn kọmiti naa n se nitori ti wọn ...