Àwon àwòrán tí ó rewà tí Lota Chukwu fi se ayeye ojó ìbí rè nígbá tí ó pé omo odún mókàndínlógbòn (29).
Gbajúgbajà arewà òsèré orílè èdè Nìjíríà tí ó n jé Lota Chukwu se ayeye odún mókàndínlógbon ojó ìbí rè ní àrà òtò, nígbà tí ó fi àwòrán tí ó dára jowá lójú, tí ó sì fi yàwá lénu púpò.
Àwon àwòrán náa rewà púpò jù, e wò ní ìsàlè.
Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwon àwòrán tí ó rewà tí Lota Chukwu fi se ayeye ojó ìbí rè nígbá tí ó pé omo odún mókàndínlógbòn (29).
Tagged with: Àṣà Yorùbá