Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwòrán ayeye ìsìnkú Obi Madubogwu.

Àwòrán ayeye ìsìnkú Obi Madubogwu.

  Akoni òsèré , Obi Madubogwu tí ó kú ní ojó kejìdínló’gbòn osù kejo ( 28/8) nígbà tí ó jèrora ìtò súgà fún bí odún díè séyìn ni won ti sin sí ìlú rè ní Ogidi ìpínlè Anambra.

Gbajúgbajà òsèré , Obi Madubogwu kú ní omo odún métàdínláàdóta (47).
E wo àwòrán ìsìnkú rè.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti